Aisan Down je aisan opolo ti n so awon to ba ni di ode. A n pe loruko John Langdon Down, eni ti o koko se alaye aisan yi ni odun 1866.