Aisha Abdulraheem
Aisha Abdulraheem (ọjọ́ ìbí Ọjọ́ kìnní oṣù kínní, ọdún 2004) jẹ́ éléréìdárayá bọ́ọ̀lù aláfọ̀wọ́gbá ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí o n sojú Chief of Naval Staff (CNS) Spikers.[1][2][3]
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ọjọ́ìbí | 1 January 2004 |
Sport | |
Erẹ́ìdárayá | Volleyball |
Club | Chief of Naval Staff VC (CNS Spikers) |
Awon ìdíje tí o ti kopa
àtúnṣeNí ọdún 2023, Aisha ati awọn akẹ́gbẹ́ rẹ lọ sojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ni Niamey, Niger Republic fún ìdíje 2023 Africa U-21 Girls Zone 3 Nations Championship.[4][5]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "CNS Spikers» rosters :: Women Volleybox". Women Volleybox. Retrieved 2024-04-19.
- ↑ Okogba, Emmanuel (2022-08-29). "14-player squad to represent Nigeria in volleyball championship". Vanguard News. Retrieved 2024-04-19.
- ↑ Awodipe, Tobi (2022-10-15). "Volleyball federation invites 30 players to camp". The Guardian Nigeria News. Archived from the original on 2024-04-19. Retrieved 2024-04-19.
- ↑ Ibeh, Ebube; Samuel, Olumayowa; Sanni, Kunle (2023-07-02). "Volleyball: Nigeria girls head to Niamey for African Zone 3 Championship". Peoples Gazette Nigeria. Retrieved 2024-04-19.
- ↑ Kuti, Dare (2023-07-03). "Volleyball: Nigeria U21 women seeking glory in Niger Rep". ACLSports. Retrieved 2024-04-19.