Aisha Falode jẹ́ oniroyin fún èrè orí pàápàá ni Nàìjíríà. Òun ní olórí fún ẹgbẹ́ agbaboolu obìnrin fún orílè-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó wá láàrin àwọn òṣìṣẹ́ tí ó kọ́kọ́ bẹẹ rẹ̀ ní ilé iṣẹ́ telefisionu tí African Independent Television. Ó ti si ṣé pelu Nigerian Telecommunication Limited àti Graduate Telephone Operators Scheme.[3][4][5] Ó jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ lórí rádíiò, ó sì má sọ̀rọ̀ nípa eré orí pàápàá.[6] Ní oṣù kìíní ọdún 2017, wọn fi jẹ olórí ẹgbẹ́ agbaboolu obìnrin fún orílè-èdè Nàìjíríà.[7]

Aisha Falode

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "NWFL board mourns death of Nasarawa Amazons chairman". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-03-04. Retrieved 2019-04-07. 
  2. Newspapers, BluePrint (2019-03-31). "Lagos agog for AITEO/NFF event, FIFA Scribe set to pick award". Blueprint (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-07. 
  3. BellaNaija.com (2014-05-04). "Aisha Falode seeks Justice for her 19 Year Son Toba who died in Dubai". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-04-07. 
  4. "I love Jean trousers and T-shirts - Falode". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2012-03-15. Retrieved 2019-04-07. 
  5. "Asia is fast becoming dominant in football - Aisha Falode". The Nation Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2017-03-17. Retrieved 2019-04-07. 
  6. "Archived copy". Archived from the original on 2014-02-15. Retrieved 2014-08-13.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Aisha Falode inaugurated board chair of Nigeria Women Football League". Premium Times. Retrieved 2017-10-05.