Aisha Masaka
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kẹ̀wá Oṣù kọkànlá ọdún 2003 | ||
Ibi ọjọ́ibí | Singida, Tanzania[1] | ||
Ìga | 1.75 m[1] | ||
Playing position | Forward, winger[1] | ||
Club information | |||
Current club | BK Häcken | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
-2021 | Young Africans | ||
2022– | BK Häcken | 0 | (0) |
National team‡ | |||
2021– | Tanzania | 4 | (2) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Aisha Masaka tí a bí ní ọjọ́ kẹ̀wá Oṣù kọkànlá ọdún 2003 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ède Tanzania tí ó ṣeré ipò iwájú lórí pápá fún BK Häcken ní Damallsvenskan àti ẹgbẹ́ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink">agbábọ́ọ̀lù</a> obìnrin ti ilẹ̀ Tanzania .
Isẹ́ ẹgbẹ́
àtúnṣeMasaka ti ṣeré fún àwọn ọ̀dọ́ Afirika ní Tanzania.
Isẹ́ òkè-òkun
àtúnṣeMasaka ti sojú fún Tanzania ní ìpele àgbà ní àkókò ìdíje COSAFA Women's championship ní ọdún 2021 .
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedLTAA
- ↑ Àdàkọ:GSA player