Aitzole Zinkunegi Araneta ( San Sebastián , Guipúzcoa, tí a bí ní ọjọ́ kejì oṣù kọkànlá ọdún 1982) jẹ́ sexologist àti transfeminist ọmọ orílẹ̀ èdè ìlú Spain. [1]

Olóṣèlú ìlú Sipania, Aitzole Araneta ní Europride ní ìlú Stockholm 2018

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Imọ idanimọ? Atunwo pẹlu Aitzole Araneta. Ile-ẹkọ Lacanian ti Psychoanalysis. Oṣu Kẹsan 21, 2017.