Ajàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Ivory Coast
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 wo orílẹ̀-èdè Ivory Coast ní inú oṣù kẹ́ta ọdún 2020.[1]
Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Ivory Coast | |
---|---|
Number of cases by District.
≥ 10 000 1 000 to 9 999 500 to 999 100 to 499 10 to 99 1 to 9 0 | |
Àrùn | COVID-19 |
Irú kòkòrò èràn | SARS-CoV-2 |
Ibi | Ivory Coast |
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́ | Wuhan, China |
Index case | Abidjan |
Arrival date | 11 March 2020 (4 years, 8 months, 1 week and 5 days) |
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn | 17,702 (as of 28 August) |
Active cases | 1,448 (as of 28 August) |
Iye àwọn tí ara wọn ti yá | 16,139 (as of 28 August) |
Iye àwọn aláìsí | 115 (as of 28 August) |
Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀
àtúnṣeNí ọjọ́ Kejìlá oṣù Kíní ọdún 2020, Àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China. Àmọ́ ó tó ọjọ́ Kẹtalélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣòkan àgbáyé létí.[2][3][4][5][6][4] [7]
Ètò ìkànìyàn olórí ò jorí tí ó yẹ kí ó wáyé ní orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire ní inú oṣù kẹrin ní ó ti ń kan ìjọba oril orílẹ̀-èdè náà lóminú bóyá yóò ṣe é ṣe látàrí ìbúr Ìbúrẹ́kẹ́ ajàkálẹ̀ àrùn aṣekú pani yí.[8]
Bí ó ṣe ń ṣẹlẹ̀ ní àwọn àsìkò kọ̀ọ̀kan
àtúnṣeÀdàkọ:COVID-19 pandemic data/Ivory Coast medical cases chart
Oṣù Kẹ́ta ọdún 2020
àtúnṣe- Ní ọjọ́ kọkanlá oṣù kẹ́ta ọdún 2020, orílẹ̀-èdè Ivory Coast ní akọsílẹ̀ akọ́kọ́ lára ẹnìkan tí ó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè náà tí ó ń darí bọ̀ láti orílẹ̀-èdè Italy. [9] Wọ́n ṣe ìtọ́jú aláàrẹ̀ náà ní ilé ìwòsàn ilé-ẹ̀kọ́ ti Treichville University Hospital ní Ìlú Abidjan. Púpọ̀ lára àwọn ènìyàn tí wón ti ní ìbáṣepọ̀ kan tabí òmìniran ni wọ́n ti ṣàwárí tí wọ́n sì ti ń ṣe àyẹ̀wò tó péye lórí wọn, gẹ́gẹ́ bí olóòtú ètò ìlera orílẹ̀-èdè náà ti ṣàlàyé. Wọ́n sì ti ní kí àwọn ard ìlú ó lọ fọkàn balẹ̀ wípé kò ní séwu. Wọ́n tún fi àwọn ìlà ìpè (143 tàbí 101) síta fún àwọn ènìyàn láti fi tó ìjọba létí bí wón bá ṣàkíyèsí àrùn yí làra ẹnikẹ́ni. Wọ́n sì tún ti fi àw9n òfin kan lélẹ̀ lẹnu ibodè orílẹ̀-èdè náà léte àti dènà àti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ ajàkálẹ̀ arùn COVID-9.[10][11]
- Ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹ́ta, ẹni akọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ní àrùn Kòrónà tún kó àrùn náà ran ìyàwó rẹ̀, tí ó mú kí iye àwọn àláàrẹ̀ COVID-9 ó jẹ́ méjì láàrín ọjọ́ méjì péré.[12]
- Ní ọjó kẹrìnlá oṣù kẹ́ta, àwọn méj méjì míràn náà tún fara kó àìsàn COVID-9 tíó mú kí ó di ènìyàn mẹ́rin tí ó ti ní àrùn yí.[13]
- Ìjọba orílẹ̀-èdè Ivory Coast kéde wípé àwọn tí wọ́n ti ní àrùn náà ti di mẹ́fà ní ọjọ́ kẹrìndínlógún, t.ẹni akọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ kó àrùn náà wọ̀lú ti gbádùn. [14] Orílẹ̀-èdè Ivory Coast kéde títi pápákọ̀ òfurufú pa fún ọjọ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún, amọ́ àyè wà fún ọmọ orílẹ̀-èdè míràn tí wọ́n wà ní orílẹ̀-èdè Ivory Coast láti padà sí Ìlú wọn kí àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè tiwọn náà tí wọ́n wà ní orílẹ̀-èdè agbáyé gbog o náà ó padà sílé láàrín kí 9jọ́ mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ó tó pé. Bákan náà ni wọ́n tún ti g ogbo ilé-ẹ̀kọ́ pátá pa fún odidi ọgbọ̀n ọjọ́.[15]
- Ní ọjọ́ kejìdínlógún sí ọjọ́ Kẹjìlélógún oṣù kẹ́ta, iye àwọn aláàrẹ̀ COVID-9 tí wọ́n ti rí ti di mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n, ìjọba orílẹ̀-èdè Ivory Coast sì kéde ìṣèjọba pàjáwìrì ní 9jọ́ kẹtalélógún oṣù kẹ́ta. [16][17] Ní ọjọ́ yí kan náà ni ìjọba ti gbogbo ẹnu ìloro orílẹ̀-èdè náà fún àsìkò kan ná.[18][19][20][21][22]
- Ní ọjọ́ Kẹrìnlélógún sí ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kẹta, iye àwọn tí wọ́n fara kó jogbo arùn COVID-9 ti di mọ́kànlélọ́gọ́rùún ènìyàn nígbà tí àwọn méjì ti ń gbádùn bò tí ó sì mú kí iye àwọn tí wọ́n ti gbádùn ó di mẹ́ta.[23][24][25][26] A 58-year-old female patient with diabetes, in a coma since 25 March, became the first fatality.[27]
- Ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n sí ọgbọ̀njọ́ oṣù kẹ́ta, wọ́n tún ṣàwárí àwọn ènìyàn tí ó tó mẹ́tàdínlọ́górin, tí àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ọgọ́rùún kan ati méjìdínlọ́gọ́rin. Nígbà tí ènìyàn mẹ́ta tún rí ìwòsàn gbà, bákan náà ni wọ́n pàdánù ẹni akọ́kọ́ sí ọwọ́ àrùn COVID-9 ní ọ̀jọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n.[28][29][30]Ẹ̀wẹ̀, wọ́n fòfin de ìgbòkègbodò ọkò ìrìnà ní àárín àwọn ìlú bí (Abidjan Department, Dabou, Azaguié, Bingerville, Grand-Bassam, Bonoua, Assinie-Mafia) láti ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dógún tí tí di ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kẹta, yàtọ̀.sí àwọn ọkọ̀ tí wọ́n bá gbé oúnjẹ àti àwọn.ohun èlò míràn. [31][32][33][34]
Oṣù Kẹ́rin ọdún 2020
àtúnṣeNí ọjọ́ Kíní sí ọjọ́ kẹta oṣù kẹrin, iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ti ní àrùn COVID-9 ti di igba àti kejìdínlógún, nígbà tí àwọn iye àwọn tí wọ́n ti rí ìwòsàn gbà ti di mọ́kàndínlógún .[35][36][37]
- Ní ọjọ́ kẹrin sí ọjọ́ kẹfà oṣù kẹrin, iye àwọn aláàrẹ̀ tí wọ́n tún rí jẹ́ 321, ní èyí tí Mínísítà fún èt ètò àbò orílẹ̀-èdè Ivory Coast ìyẹn ọ̀gbẹ́ni Hamed Bakayoko wà nínú wọn. Àwọn tí wọ́n rí ìwòsàn gbà lọ sókè sí mọ́kànlélógójì nígbà tí àwọn ènìyàn mẹ́ta mìíràn ṣaláìsí.[38][39][40] Since the start of the outbreak, 323 cases had been confirmed of which 41 had recovered and 3 had died.[41] The Ministry of Health and Public Hygiene published a list of sites, in and around Abidjan, for testing: Yopougon, Abobo, Marcory, Koumassi and Port-Bouët; treatment: Treichville, Cocody, Grand-Bassam, Yopougon, Abidjan, and Anyama; quarantine (Marcory); and for analysis (Pasteur Institute Abidjan).[42] The announcement led to days of violent protests in Youpogon and Koumassi.[43]
- Ní ọjọ́ keje sí ọjọ̀ Kẹtàlá oṣù kẹrin, iyw àwọn ènìyàn tíwọ́n ti ní àrùn yí ti di ọgọ́rùún mẹ́fà àti mèrìndínlógbọ̀n , iye àwọn ènìyàn tí wọ̀n rí ìwòsàn gbà jẹ́ 89, nígbà tí àwọn mẹ́fa ti papò dà.[44][45] The number of recovered patients rose by 7, to 48.
- Ní ọjọ́ Kẹrìnlá sí kọ̀kànlélógún, iye àwọn tí wọ́n rí ìwòsàn gbà jẹ́ igba àti mẹ́ẹ̀èdọ́gbọ̀n, nígbà tí wọ́n ṣàwárí iye àwọn ènìyàn 344 míràn tí wọ́n ní arùn COVID-9, iye àwọn tí eọ́ papò dà jẹ́ mẹ́wàá lápapọ̀. [51][52] Ìjọba ṣàfikún òfin kónílé-ó-gbélé títí di ọgbọ̀njọ́ oṣù kèrin ntí wọ́n sì tún ní kí ilé-ẹ̀kọ́ ó wà ní títìpa títí di ọjọ́ kẹtàdínlógún oṣù Karùún. [53]
[54] Secretary-general Patrick Achi announced that he had tested positive.[55][56][57][58][59][60][61]
- Wọ́n ṣàwárí àwọn mẹ́rìndínlógójì míràn nígbà tí àwọn àpapọ̀ iye àwọn tí.wọ́n rí ìwòsàn gbà jẹ́ ọgọ́rún mẹ́ta ati mèwaá. Àwọn tí wọ́ papò dà jẹ́ mẹ́rìnlá lápapọ̀.[62]
- Ní ọjọ́ kẹtalélógún sí ọgbọ̀njọ́ oṣù kẹ́rin, iye àwọn tí wọ́n ní àrùn COVID-9 jẹ́ 1275, nígbà tí àpapọ̀ iye àwọn tí wọ́n rí ìwòsàn gbà jẹ́ 527, bákan naa ni iye àwọn ènìyàn tí wọ́n papò dà náà jẹ́ mẹ́wàá ní in oṣù kẹrin.[63][64][65][66]
Oṣù Karùún ọdún 2020
àtúnṣe- Ní ọjọ́ Kíní oṣù Karùún. Wọ́nr í akọsílẹ̀ méjìdínlọ́gọ́ta, nígbà tí àwọn aláàrẹ̀ mẹ́tàlélógún rí ìwòsàn gbà, tí àwọn mẹ́ẹ̀ẹ́dógún ṣaláìsí lápapọ̀.Àṣìṣe ìtọ́kasí: Closing
</ref>
missing for<ref>
tag - Ní ọjọ́ kejì oṣù karùún, àwọn ènìyàn kọkàndínlọ́gbọ̀n ní wọ́n tún rí tí wọ́n fara kó àrùn COVID-9, nígbà tí àwọn ènìyàn mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n rí ìwòsàn gbà.[71]
- Ní ọjọ́ kẹta sí ọjọ́ keje oṣù Karùún, iye àwọn ènìyàn tí wọ́n ní arùn Kòrónà jẹ́ 177 tí ó mú kí iye àwọn aláàrẹ̀ naa ó di 1571, iye àwọn tí wọ́n rí ìwòsàn gba jẹ́ 120 tí ó mú kí iye wọn lápapọ̀ jẹ́ 742, nígbà tí iye àwọn tí wọ́n kú jẹ́ ogún lápapọ̀. Lẹ́yìn èyí, ìjọba orílẹ̀-èdè Ivory Coast kéde ré wípé kí.àwọn ilé-ékó g og o padà ní Ìlú [[Abjan 34ryr6rrt On 3 May there were two fatalities, 36 confirmed cases and 31 recoveries. The total number of confirmed cases stood at 1398 of which 653 had recovered and 17 deceased.[72]
- Ni ojo kerin osu karuun, won sawari eniyan merinlelogbon miran, ti awon ogoji eniyan si ri iwosan gba.[73]
- Ni ojo karuun iye awon ti won tun ni arun yi je mejilelogbon, ti o mu iye awon ti won ti ni arun yi lapapo je 1464 lapapo, ti awon mejo si ri iwosan gba. Bakan naa ni awon mejidinlogun padanu emi won si owo aisan Korona.[74][75]
- Ni ojo keje osu karuun, won ri akosile marundinlogota, awon aadoje ati ogoji o le meji eniyan ri iwosan gba lapapo. Iye awon ti won padanu emi won je ogun. Ijoba orile-ede Ivory Coast kede wipe awon yoo mu irorun ba igbokegbodo lilo bibo ni ilu Abidjan ni ojo keji, ti o fi mo awon ile-eko gbogbo titi di ojo keedogun osu karuun. Bakan naa ni awon yoo mu adinku ba ile koko irina ni ale si wakati metalelogun lati ojo kejo osu karuun.[76][77]Àṣìṣe ìtọ́kasí: Closing
</ref>
missing for<ref>
tag - On the same day, residents in the Yopougon district of Abidjan destroyed a testing centre that was being built.[78]
Osu Kefa odun 2020
àtúnṣe- Awon mokanlelogorun ni won tu sawari ni ojo kini ose kefa, nigba ti awon mejilelogbon ri iwosan gba.[79]
- Ni ojo keji si ojo karuun osu kefa, iye awon ti won tun lugbadi arun yi je ogorun merin o le aadorin. Nigba ti awon ti won ri iwosan gba je or=goirun ogorun kan o le merindinlogoji, bakan naa ni iye awon ti won padanu emi won si owo arun Korona je meta. [80][81][82][83]
- Ni ojo kefa si ojo kejila osu kefa, egberun kan ati ogorun meta o le meedogun. Nigba ti awon ti won ri iwosan gba je egberun merin ati ogorun meji o le mokanlelogoji. iye awon ti won ku je marundinlaadota lapapo.[84][85][86][87][88][89][90]
- Ni ojo keedogbon si ogbonjo osu kefa, iye awon ti won ti fara kasa arun COVID-19 lapapo je 9499, nigba ti awon ti won ri iwosan gba goke si 4273, bakan naa ni iye awon ti won padanu emi won si inu aisan COVID-19 lapapo je 68. iye awon ti o ku ti won ko tii ri iwosan gba ti won ko si ku je 255 lapapo.[91] The National Security Council decided that domestic flights could be resumed from 26 June and international flights from 1 July, while land and sea borders will remain closed.[92]
Osu kejo odun 2020
àtúnṣe- Ni ojo kini osu kejo, awon mejilelogota eniyan ni won fara kasa arun COVID-19, nigba ti iye awon ti won ti ni arun yi lapapo je 16109. Bakan naa ni awon iye awon ti won ri iwosan gba je 11750 lapapo.[98]
Awon 73 eniyan ni won tun ni arun yi ni ojo keji osu kejo, ti awon mokanlelaadota ri iwosan gba.[99] Awon merindinlogoji ni won sawari ni ojo keta, awon merinlelaadorin ni won gbadun lapapo ti o mu iye awon ti won ti gbadun goke si 11887.[100] awon 73 ni won ri ni ojo kerin, ti o mu ki iye awon alaare naa goke si 16293. Awon mejo o le ogota eniyan ni won ri iwosan gba nigba ti apapo iye won je 11955. Awon metalelogorun ni won ti gbekuru je lowo ebora lapapo.[101]
- Lati ojo karn osu kejo si ogbonjo osu kejo, awon eniyan ti won ti ni arun COVID-19 je 17948, awon eniyan ti won ti ri iwosan gba lapapo je 16699.[102][103][104][105][106][107]
- Ni ojo kokanlelogbon osu kejo, won tun ri akosile tuntun ti o to ogorun kan o le mokandinlogun ti o mu ki iye awon ti won ni aisan yi o je 18067, nigba ti iye awon ti won ri iwosan gba lapapo je 16699. Iye awon ti won ku je 117 nipari osu kejo.[108]
Ẹ tún lè wo
àtúnṣe- COVID-19 pandemic in Africa
- COVID-19 pandemic by country and territory
- Impact of the COVID-19 pandemic on aviation
- Impact of the COVID-19 pandemic on cinema
- Impact of the COVID-19 pandemic on education
- Impact of the COVID-19 pandemic on religion
- Impact of the COVID-19 pandemic on politics
- Impact of the COVID-19 pandemic on sports
- Impact of the COVID-19 pandemic on television
- Impact of the COVID-19 pandemic on tourism
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Premier cas de Covid-19 en Côte d'Ivoire" (in fr). Le Monde.fr. 2020-03-11. https://www.lemonde.fr/afrique/article/2020/03/11/premier-cas-de-covid-19-en-cote-d-ivoire_6032649_3212.html.
- ↑ Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus.
- ↑ 4.0 4.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Future scenarios of the healthcare burden of COVID-19 in low- or middle-income countries, MRC Centre for Global Infectious Disease Analysis at Imperial College London.
- ↑ Technical Brief on the Implications of COVID-19 on Census. UNFPA. 2020. https://www.unfpa.org/sites/default/files/resource-pdf/Census_COVID19_digital.pdf.
- ↑ "Ivory Coast confirms first case of coronavirus". Daily Sabah. 11 March 2020. Retrieved March 11, 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Côte d'Ivoire : un premier cas confirmé de coronavirus, les autorités appellent au calme – Jeune Afrique". JeuneAfrique.com (in Èdè Faransé). 2020-03-11. Retrieved 2020-03-11.
- ↑ "Premier cas de coronavirus confirmé en Côte d'Ivoire" (in fr). BBC News Afrique. 2020-03-11. https://www.bbc.com/afrique/region-51840497.
- ↑ "Coronavirus : Un deuxième cas testé positif en Côte d'Ivoire". AbidjanTV.net (in Èdè Faransé). 2020-03-12. Retrieved 2020-03-12.
- ↑ "Coronavirus : 3 nouveaux cas confirmés en Côte d'Ivoire". Agence Ecofin (in Èdè Faransé). 2020-03-15. Retrieved 2020-03-16.
- ↑ "Coronavirus : le bilan passe à 6 confirmés en Côte d'Ivoire". Atoo.ci (in Èdè Faransé). 2020-03-16. Archived from the original on 17 March 2020. Retrieved 2020-03-18.
- ↑ "West Africa clamps down on borders as coronavirus cases rise". outlookindia.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-03-17. Retrieved 2020-03-19.
- ↑ "Les médias ivoiriens appelés à ne pas diffuser les informations 'non certifiées' sur le coronavirus". APA (in Èdè Faransé). 2020-03-19. Retrieved 2020-03-19.
- ↑ "Coronavirus : la Côte d'Ivoire compte 14 cas confirmés dont un guéri, à la date du 20 mars 2020". www.gouv.ci (in Èdè Faransé). 2020-03-21. Retrieved 2020-03-22.
- ↑ "Coronavirus : les frontières terrestres, maritimes et aériennes ivoiriennes fermées à tout traffic de personnes, à compter du 22 mars 2020, à minuit". www.gouv.ci (in Èdè Faransé). 2020-03-21. Retrieved 2020-03-22.
- ↑ "Trois (3) nouveaux cas de maladie à Coronavirus annoncés ce 21 mars, portant à 17 les nombres de cas confirmés en Côte d'Ivoire". RTI.ci (in Èdè Faransé). 2020-03-21. Retrieved 2020-04-24.
- ↑ "Le ministère de la santé annonce ce dimanche, la détection de 8 nouveaux cas portant à 25 le nombre de cas confirmés en Côte d'Ivoire". news.abidjan.net (in Èdè Faransé). 2020-03-22. Retrieved 2020-03-23.
- ↑ "Ivory Coast, Senegal declare emergencies, impose curfews in coronavirus response". Reuters (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 23 March 2020. Retrieved 23 March 2020.
- ↑ "Report d'isolement d'Abidjan: Un grand danger guette la Côte d'Ivoire". afrique-sur7.fr/ (in Èdè Faransé). 27 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-27.
- ↑ "Coronavirus: 48 nouveaux cas déclarés ce mardi portant à 73 le nombre de cas confirmés en Côte d'Ivoire (Officiel)". news.abidjan.net/ (in Èdè Faransé). 24 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-24.
- ↑ "Coronavirus: 7 nouveaux cas confirmés ce mercredi 25 mars portant à 80 le nombre de cas en Côte d'ivoire (officiel)". news.abidjan.net (in Èdè Faransé). 25 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-25.
- ↑ "Covid19: 16 nouveaux cas confirmés en Côte d'ivoire ce jeudi 26 mars portant le nombre à 96 cas.(ministère de la santé et de l'hygiène publique)". news.abidjan.net/ (in Èdè Faransé). 26 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-27.
- ↑ "Covid-19: la Côte d'Ivoire franchit la barre de 100 cas avec 5 nouveaux cas portant le nombre d'infectés à 101 dont 3 guéris (Ministre de la Santé)". news.abidjan.net/ (in Èdè Faransé). 27 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-28.
- ↑ "Coronavirus : En Côte d'Ivoire, plusieurs décès occasionnés par les maladies chroniques". RTI.ci (in Èdè Faransé). 23 April 2020. Archived from the original on 27 April 2020. Retrieved 2020-04-23.
- ↑ "Coronavirus : la Côte d'Ivoire est à 140 cas confirmés". abidjantv.net (in Èdè Faransé). 29 March 2020. Retrieved 2020-03-29.
- ↑ "Ivory Coast records first coronavirus death: minister". 20 March 2020. Retrieved 13 April 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Covid19 : la Côte d'Ivoire enregistre 25 nouveaux cas portant ainsi à 165 le nombre de cas confirmés dont 4 guéris et 1 décès (Officiel)". news.abidjan.net/ (in Èdè Faransé). 29 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "Coronavirus : Vive tension au pont à péage après l'isolement d'Abidjan". afrique-sur7.fr (in Èdè Faransé). 30 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-30.
- ↑ "Coronavirus : Arrêté portant interdiction de circulation des personnes et des véhicules". abidjantv.net/ (in Èdè Faransé). 17 March 2020. Retrieved 2020-07-01.
- ↑ "Covid-19 : 3 nouveaux cas enregistrés, portant à 168 le nombre de cas confirmés dont 06 guéris et 01 décès. (Ministère)". abidjantv.net/ (in Èdè Faransé). 30 March 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-03-31.
- ↑ "Coronavirus Côte d'Ivoire : 11 cas à l'intérieur du pays sur 179". AfrikSoir.net (in Èdè Faransé). 31 March 2020. Archived from the original on 1 April 2020. Retrieved 2020-03-31.
- ↑ "Le nombre de malades de COVID 19 en Côte d'Ivoire passe à 190 avec 11 nouveaux cas (Ministre)". AIP.ci (in Èdè Faransé). 1 April 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-04-02.
- ↑ "Coronavirus : 4 nouveaux cas confirmés et 6 nouveaux guéris en Côte d'Ivoire (Ministre)". AIP.ci (in Èdè Faransé). 2 April 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-04-02.
- ↑ "Coronavirus : 24 nouveaux cas, la Côte d'Ivoire franchit la barre des 200 cas confirmés". AfrikSoir.net (in Èdè Faransé). 3 April 2020. Retrieved 2020-04-04.
- ↑ "Covid-19 en Côte d'Ivoire : Déjà 245 malades, San-Pedro et Toulepleu". Afrique-sur7.fr (in Èdè Faransé). 4 April 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-04-05.
- ↑ "Coronavirus : 16 nouveaux cas de contamination, 2 décès". linfodrome.com (in Èdè Faransé). 5 April 2020. Retrieved 2020-04-07.
- ↑ "Côte d'Ivoire Defence Minister Contracts Coronavirus". PeaceFMonline.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 7 April 2020. Retrieved 2020-04-07.
- ↑ "Coronavirus : 62 nouveaux cas d'infection à Covid-19 ont été enregistrés, portant à 323 ce 6 Avril 2020". FratMat.info (in Èdè Faransé). 6 April 2020. Retrieved 2020-04-07.
- ↑ "Covid19/Abidjan : voici les sites de prélèvements, de prise en charge, de quarantaine...". Pressecôted’ivoire.ci (in Èdè Faransé). 6 April 2020. Retrieved 2020-04-08.
- ↑ "Côte d'Ivoire : Koumassi dit non à l'installation d'un centre de dépistage du coronavirus dans la Commune". AbidjanTV.net (in Èdè Faransé). 7 April 2020. Retrieved 2020-04-08.
- ↑ "Coronavirus : 26 nouveaux cas d'infection à COVID-19 enregistrés, ce mardi". Pressecôted’ivoire.ci (in Èdè Faransé). 7 April 2020. Retrieved 2020-04-07.
- ↑ "La Côte d'Ivoire proroge le couvre feu avec une grâce présidentielle pour un millier de prisonniers". FinancialAfrik.com (in Èdè Faransé). 8 April 2020. Retrieved 2020-04-08.
- ↑ "Communiqué du Conseil National de Sécurité (CNS) du jeudi 9 avril 2020". gouv.ci (in Èdè Faransé). 9 April 2020. Retrieved 2020-04-10.
- ↑ "Covid-19 : La Côte d'Ivoire proche de franchir la barre des 500 cas". Afrique-sur7.fr (in Èdè Faransé). 10 April 2020. Archived from the original on 13 April 2020. Retrieved 2020-04-12.
- ↑ "Avec 53 nouveau cas, la Côte d'Ivoire franchit le cap de 500 malades du Covid-19". APAnews.net (in Èdè Faransé). 11 April 2020. Retrieved 2020-04-12.
- ↑ "Covid-19 : La Côte d'Ivoire enregistre 27 nouvelles guérisons et 41 nouveaux cas confirmés". Informateur.info (in Èdè Faransé). 12 April 2020. Retrieved 2020-04-12.
- ↑ "Coronavirus : 52 nouveaux cas enregistrés ce lundi de pâques". Pressecôted'ivoire.ci (in Èdè Faransé). 13 April 2020. Retrieved 2020-04-13.
- ↑ "Côte d'Ivoire-AIP/COVID-19 : Le nombre de contaminés est désormais de 638 dont 114 guéris". AIP.ci (in Èdè Faransé). 14 April 2020. Archived from the original on 24 April 2020. Retrieved 2020-04-14.
- ↑ "Coronavirus : La Côte d'Ivoire enregistre un total de 146 guéris". Informateur.info (in Èdè Faransé). 15 April 2020. Retrieved 2020-04-15.
- ↑ "COVID-19 : L'Etat d'urgence prorogé jusqu'au 30 avril". Abidjan.net (in Èdè Faransé). 16 April 2020. Retrieved 2020-04-18.
- ↑ "Côte d'Ivoire : 34 nouveaux cas de Coronavirus, 47 nouveaux guéris, espoir, le taux de guérison n'en finit plus de progresser". Koaci.com (in Èdè Faransé). 16 April 2020. Retrieved 2020-04-16.
- ↑ "Close ally of Ivory Coast leader contracts coronavirus". 17 April 2020. Archived from the original on 3 June 2020. https://web.archive.org/web/20200603073608/https://www.dispatchlive.co.za/news/africa/2020-04-17-close-ally-of-ivory-coast-leader-contracts-coronavirus/. Retrieved 20 April 2020.
- ↑ "Coronavirus : 54 nouveaux cas d'infection, 27 nouveaux guéris". linfodrome.com (in Èdè Faransé). 17 April 2020. Retrieved 2020-04-18.
- ↑ "Côte d'Ivoire : Qui sont les deux dernières victims du Coronavirus ?". AfrikSoir.net (in Èdè Faransé). 19 April 2020. Retrieved 2020-04-19.
- ↑ "Covid-19/Point de la situation : 46 nouveaux cas d'infection enregistrés, portant à 847 le nombre total de cas confirmés. 21 nouveaux guéris et 1 décès". Fratmat.info (in Èdè Faransé). 19 April 2020. Retrieved 2020-04-19.
- ↑ "Coronavirus : Quelques données sur la maladie en Côte d'Ivoire, régions touchées, les cas par villes et quartiers...". Fratmat.info (in Èdè Faransé). 21 April 2020. Retrieved 2020-04-21.
- ↑ "Côte d'Ivoire / COVID_19 : 32 nouveaux cas d'infection, 27 nouveaux guéris et 1 décès". AbidjanTV.net (in Èdè Faransé). 20 April 2020. Retrieved 2020-04-20.
- ↑ "Coronavirus : Voici le point de ce mardi 21 avril". Pressecôted'ivoire.ci (in Èdè Faransé). 21 April 2020. Retrieved 2020-04-21.
- ↑ "Coronavirus : l'Afrique face à la pandémie mercredi 22 avril". rfi.fr (in Èdè Faransé). 22 April 2020. Retrieved 2020-04-22.
- ↑ "Coronavirus : Plus de 1000 cas confirmés en Côte d'Ivoire (Ministère de la Santé)". RTI.ci (in Èdè Faransé). 23 April 2020. Archived from the original on 6 July 2020. Retrieved 2020-04-23.
- ↑ "Coronavirus : l'Afrique face à la pandémie vendredi 24 avril". rfi.fr (in Èdè Faransé). 24 April 2020. Retrieved 2020-04-24.
- ↑ "COVID 19 : le nombre de cas confirmés passe à plus de 1100 en Côte d'Ivoire". Abidjan.net (in Èdè Faransé). 25 April 2020. Retrieved 2020-04-25.
- ↑ "Covid-19 : Point de la situation de ce dimanche 26 avril". Pressecôted'ivoire.ci (in Èdè Faransé). 26 April 2020. Retrieved 2020-04-26.
- ↑ "Côte d'Ivoire-AIP / Covid-19 : le bilan passe à 1164 avec 14 nouveaux cas confirmés". AIP.ci (in Èdè Faransé). 27 April 2020. Archived from the original on 8 May 2020. Retrieved 2020-04-27.
- ↑ "Côte d'Ivoire : Près de 50% des malades du Covid-19, guéris". Afrique-sur7.fr (in Èdè Faransé). 28 April 2020. Archived from the original on 20 July 2020. Retrieved 2020-04-28.
- ↑ "Côte d'Ivoire-AIP/Covid 19 : le bilan passe à 1238 cas confirmés". AIP.ci (in Èdè Faransé). 29 April 2020. Archived from the original on 10 May 2020. Retrieved 2020-04-29.
- ↑ "Côte d'Ivoire-AIP/Covid-19 : 37 nouveaux cas confirmés (ministre)". AIP.ci (in Èdè Faransé). 30 April 2020. Archived from the original on 12 May 2020. Retrieved 2020-04-30.
- ↑ "Côte d'Ivoire-AIP/COVID-19 : 29 nouveaux cas enregistrés en Côte d'Ivoire (Ministère de la santé)". AIP.ci (in Èdè Faransé). 3 May 2020. Archived from the original on 20 July 2020. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "Trente-six nouveaux cas confirmés de Covid-19 en Côte d'Ivoire". AIP.ci (in Èdè Faransé). 3 May 2020. Archived from the original on 15 May 2020. Retrieved 2020-05-03.
- ↑ "Côte d'Ivoire-AIP/34 nouveaux cas confirmés de Covid-19 et 40 nouveaux malades guéris". AIP.ci (in Èdè Faransé). 4 May 2020. Archived from the original on 16 May 2020. Retrieved 2020-05-05.
- ↑ "Coronavirus : 32 nouveaux cas, 8 nouveaux guéris et 1 nouveau décès". linfodrome.com (in Èdè Faransé). 5 May 2020. Retrieved 2020-05-05.
- ↑ "Covid-19 : La barre des 1500 cas déclarés positifs en Côte d'Ivoire, 721 guérisons et 18 décès". Afrique-sur7.fr (in Èdè Faransé). 6 May 2020. Archived from the original on 20 July 2020. Retrieved 2020-05-06.
- ↑ "Côte d'Ivoire : assouplissement des mesures contre le coronavirus en province". rfi.fr (in Èdè Faransé). 8 May 2020. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "Côte d'Ivoire : Dans l'attente du 15 mai, 31 nouveaux cas de Coronavirus, 12 nouveaux guéris et pas de décès". Koaci.com (in Èdè Faransé). 8 May 2020. Retrieved 2020-05-08.
- ↑ "Crowd in ICoast destroys coronavirus test centre". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-04-06. Retrieved 2020-06-15.
- ↑ "Covid-19 : 1er juin 2020 : 118 nouveaux cas sur 611 prélèvements, 32 guéris et 00 décès. Au total 2951 cas confirmés, 1467 guéris, 33 décès et 1451 cas actifs". AIP.ci (in Èdè Faransé). 1 June 2020. Archived from the original on 29 July 2020. Retrieved 2020-06-01.
- ↑ "La Côte d'Ivoire franchit la barre des 3000 cas confirmés de coronavirus (DG Santé)". AIP.ci (in Èdè Faransé). 2 June 2020. Archived from the original on 28 July 2020. Retrieved 2020-06-02.
- ↑ "Covid-19 : 86 nouveaux cas ce mercredi 03 juin 2020 portant à 3110 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 29 nouveaux guéris ; 2 nouveaux décès". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 3 June 2020. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Covid-19 : 152 nouveaux cas ce jeudi 04 juin 2020 portant à 3262 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 54 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 4 June 2020. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Covid-19 : 169 nouveaux cas ce vendredi 05 juin 2020 portant à 3431 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 20 nouveaux guéris ; 1 nouveau décès". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 5 June 2020. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Covid-19 : 126 nouveaux cas ce samedi 06 juin 2020 portant à 3557 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 146 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 6 June 2020. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Covid-19 : 182 nouveaux cas ce dimanche 07 juin 2020 portant à 3739 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 68 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 7 June 2020. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Covid-19 : 142 nouveaux cas ce lundi 08 juin 2020 portant à 3881 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 51 nouveaux guéris ; 2 nouveaux décès". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 8 June 2020. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Point de la situation de la maladie à Coronavirus du 9 juin 2020". Pressecôted'ivoire.ci (in Èdè Faransé). 9 June 2020. Retrieved 2020-06-09.
- ↑ "Côte d'Ivoire : 186 nouveaux cas de covid 19 enregistrés ce mercredi". L’expressionci.com (in Èdè Faransé). 10 June 2020. Retrieved 2020-06-10.
- ↑ "Point de la situation de la maladie à Coronavirus du jeudi 11 juin 2020". Pressecôted'ivoire.ci (in Èdè Faransé). 11 June 2020. Retrieved 2020-06-12.
- ↑ "Côte d'Ivoire-AIP/Covid-19 : 280 nouveaux cas enregistrée en 24 heures (ministère)". AIP.ci (in Èdè Faransé). 12 June 2020. Archived from the original on 28 July 2020. Retrieved 2020-06-12.
- ↑ "Coronavirus : 170 nouveaux cas enregistrés, 68 nouveaux guéris et 2 nouveaux décès ce jeudi". linfodrome.com (in Èdè Faransé). 25 June 2020. Retrieved 2020-06-25.
- ↑ "Côte d'Ivore/Covid-19 : reprise des vols internationaux à partir du 1er juillet 2020". Abidjan.net (in Èdè Faransé). 25 June 2020. Retrieved 2020-06-25.
- ↑ "Covid-19 en Côte d'Ivore : voici le point ce 26 juin 2020". IvoireSoir.net (in Èdè Faransé). 26 June 2020. Retrieved 2020-06-26.
- ↑ "Covid-19 en Côte d’Ivoire : voici le point ce 27 juin 2020". IvoireSoir.net (in Èdè Faransé). 27 June 2020. Retrieved 2020-06-27.
- ↑ "Covid-19 : 157 nouveaux cas ce dimanche 28 juin 2020 portant à 9101 cas confirmés en Côte d’Ivoire ; 86 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 28 June 2020. Retrieved 2020-06-29.
- ↑ "Covid-19 : le point de la situation du lundi 29 juin 2020". Pressecôted'ivoire.ci (in Èdè Faransé). 29 June 2020. Retrieved 2020-06-29.
- ↑ "Point de la situation de la maladie à Coronavirus du lundi 30 juin 2020". Pressecôted'ivoire.ci (in Èdè Faransé). 30 June 2020. Retrieved 2020-06-30.
- ↑ "Coronavirus : 62 nouveaux cas enregistrés et 322 nouveaux guéris ce samedi". linfodrome.com (in Èdè Faransé). 1 August 2020. Retrieved 2020-08-01.
- ↑ "Coronavirus : 73 nouveaux cas enregistrés et 51 nouveaux guéris ce dimanche". linfodrome.com (in Èdè Faransé). 2 August 2020. Retrieved 2020-08-02.
- ↑ "Covid-19 : 38 nouveaux cas ce lundi 03 août 2020 portant à 16220 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 86 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 3 August 2020. Retrieved 2020-08-03.
- ↑ "Covid-19 en Côte d’Ivoire : voici le point de la situation ce 4 août 2020". YECLO.com (in Èdè Faransé). 4 August 2020. Retrieved 2020-08-04.
- ↑ "Covid-19 : 56 nouveaux cas ce mercredi 05 août 2020 portant à 16349 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 236 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 5 August 2020. Retrieved 2020-08-05.
- ↑ "Le point de la situation de la COVID-19 du 6 Août 2020". Pressecôted’ivoire.ci (in Èdè Faransé). 6 August 2020. Retrieved 2020-08-06.
- ↑ "Covid-19 au 07 août : 77 nouveaux cas sur 924 prélèvements, 159 nouveaux guéris, 01 décès . Au total, 16524 cas confirmés, 12802 guéris, 104 décès, 3618 cas actifs". AIP.ci (in Èdè Faransé). 7 August 2020. Retrieved 2020-08-07.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ "Covid-19 : 96 nouveaux cas ce samedi 08 août 2020 portant à 16620 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 91 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 8 August 2020. Retrieved 2020-08-08.
- ↑ "Coronavirus : 95 nouveaux cas enregistrés, 33 nouveaux guéris et 1 nouveau décès ce dimanche". linfodrome.com (in Èdè Faransé). 9 August 2020. Retrieved 2020-08-09.
- ↑ "Covid-19 : 83 nouveaux cas ce lundi 10 août 2020 portant à 16798 cas confirmés en Côte d'Ivoire ; 126 nouveaux guéris". Educarriere.ci (in Èdè Faransé). 10 August 2020. Retrieved 2020-08-18.
- ↑ "Covid-19 en Côte d’Ivoire : voici le point au 31 août 2020". IvoireSoir.net (in Èdè Faransé). 31 August 2020. Retrieved 2020-08-31.