Ajibade Gbadegesin Ogunoye
Ajibade Gbadegesin Ogunoye je agbejoro, osise Ipinle Ondo tele. O si je oba Ilu Owo.[1]
Olowo Ajibade Gbadegesin Ogunoye | |
---|---|
Ogunoye ni àsìkò ọdún Ìgògò ní ìlú Ọ̀wọ̀ | |
Reign | 2019 – present |
Predecessor | Folagbade Olateru Olagbegi III |
Spouse | Olori Olanike Ogunoye |
Father | Adekola Ogunoye II |
Mother | Olori Adenike Yeyesa Ogunoye |
Born | 6 Oṣù Keje 1966 Owo, Ondo State, Nigeria |
Ise re
àtúnṣeO je oba leyin ti oba ana, Folagbade Olateru Olagbegi III papo'da. Kí ó tó di Ọba, ó ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìjọba Ìpínlẹ̀ Òndó gẹ́gẹ́ bí Adarí ìṣàkóso ìṣúná lábẹ́ ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo.[2][3]
Awon itokasi
àtúnṣe- ↑ "Gbadegesin becomes new Olowo Of Owo - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. 2019-07-13. Archived from the original on 2022-01-29. Retrieved 2022-01-29.
- ↑ "Olowo-elect : I’m not surprised Prince Ogunoye emerged almost unopposed – Ikubese". Vanguard News. 2019-08-10. Retrieved 2022-01-29.
- ↑ "BREAKING: Ogunoye Ajibade Gbadegesin emerges as Olowo elect -". TVC News. 2019-07-12. Retrieved 2022-01-29.
'