Ajibola Famurewa
Ajibola Famurewa je olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. O je omo ile ìgbìmò asoju ìjọba àpapọ̀ to n sójú Atakunmosa East / Atakunmosa West /Ijesa ti ìpínlè Osun ni ile ìgbìmò asofin àgbà kẹjọ. [1]
Ni 2020, o jẹ alága ati Aláṣẹ ti Osun State Universal Basic Education (SUBEB) [2] [3]