Akáríayé unjuwe ohun ( ile-ise, ede, tabi agbajo kan) to nibasepo mo ju ori;e-ede kan lo. Fun apere, ofin akariaye, unsise ni awon orile-ede to po ati nigba miran ka kiri gbogbo Ile-aye, ati ede akariaye je ede kan ti won unso ni awon orile-ede to ju eyokan lo.


ItokasiÀtúnṣe