Isé ọ̀pẹ-kíkọ jé ọ̀kan lára àwọn isé ìbílẹ̀ ilè Yorùbá. Nínú Isé yìí bákan náà ni a ti máa n gba ògùrò tàbí ẹmu.

Akọ̀pẹ ń gun Igi-ọpẹ.