Akarigbo ti Remo tàbí Olọ́run Remo jẹ́ oyè ọba tí ọba Yorùbá ti ilú Sagamu maa ń jẹ. Ìlú yìí àti àwọn agbègbè rẹ̀ jẹ́ ara ilú tí wọ́n maá ń pè ní Ìjẹ̀bú.[1]

Ìpinlẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ àtúnṣe

 
Àfin Àkárìgbò ti ìlú Remo

Ọba Ìlù Remo ti wà tipẹ́ láti ìgbàtí tí ọmọ ọba Ọ̀yọ́ tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Obanta ti dá ilù Ìjẹ̀bú sílẹ̀ àti ìgbà tí ọmọ ọba Àkárìgbò ti wá sí Ìwòoòrùn ìlú náà ní bíi ọ̀rundún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn. Wọ́n maa ń fi orúkọ yìí dá àwọn ọba Sagamu, lọ́lá ní orúkọ ọmọ ọba àkọ́kọ́.

Orí ìtẹ́ àwọn ọba Àkárìgbò kọ́kọ́ wà ní agbègbè Remo lẹ́gbẹ́ Offin, ilú méjì tí ó wà ní ìwọ̀ oòrùn ibi tí ìtẹ́ náà wà nísìn. Látàrí òwò ẹrú ní Dahomey àti ogun tí ó wáyé láàrín àwọn olóyè Abẹ́òkúta àti àwọn Ọba Dahomey, tí ó fàá kí àwọn Yòrúbá kúrò ní Abẹ́òkúta àti ìwọ̀ oòrùn Dahomey lọ sí Àkàrígbò tí ó sì jẹ́ kí ó wọ́n wà ní ìṣàkóso àwọn Oba Àkárígbò. Ohun tí ó tún fàá ni ṣíṣubú Òde Ọ̀yọ́ tí ó ṣelẹ̀ dé Gúúsù  Ìjẹ̀bú àti ogun Jihad tí ó ṣẹlẹ̀ ní ilẹ̀ Hausa, tí Usman dan Fodio tí ó jẹ́ Fúlàní ṣe adarí rẹ̀. Láti lè dojú ìjà kọ́ ìhàlẹ̀ yìí, àwọn olórí ẹ̀gbẹ́ kọ̀kan sì dá Sagamu sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bi ibi tí àwọn ènìyàn tí ogún bá lé kúrò ní gúúsù àti ìwọ̀ oòrùn lè sá pamọ́ sí.[2]

Àfin Àkárìgbò ti ìlú Remo àtúnṣe


Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe