Akin Ògúngbè

Òṣéré orí ìtàgé

Akin Ògúngbè tí wọ́n bí ní ọdún 1934 tí ó sì kú ní oṣù kọkànlá ọdún 2012 jẹ́ òṣèré orí ìtàgé, adarí eré orí ìtàgé àti agbéréjáde. Ọmọ rẹ̀ ni gbajúgbajà òṣèré, olóòtú àti olùdarí sinimá-àgbéléwò ṣẹ́gun Ògúngbè [1]

Akin Ogungbe
Ọjọ́ìbíChristopher Akintola Ogungbe
1934
Abeokuta, Ogun State, Nigeria
AláìsíNovember 28, 2012
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànIreke Onibudo and Baba Ibeji
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́
  • actor
  • filmmaker
  • producer
  • director
Ìgbà iṣẹ́1953-2012
Gbajúmọ̀ fúnStage play

Drama

Movie
Àwọn olùbátanSegun Ogungbe (son) Claudius Olaseinde Ogungbe (sibling)

Ìgbà èwe àti ááyan ìkẹ́kọ̀ọ́Àtúnṣe

A bí ní ọdún 1934 ní ìlú Abẹ́òkúta tí ó jẹ́ olú ìlú ìpínlè Ògùn ní apá gúúsù ìwọ̀-oòrùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó sì kú ní oṣù Kejìlá ọdún 2012. Ó ń gbé ní ọ̀dọ̀ ìyá ìyá rẹ̀ níbi tí ó ti ń kọ́ iṣẹ́ télọ̀. "A terrible life" ni eré orí ìtàgé àkọ́kọ́ rẹ̀ tí orúkọ rẹ̀ nínú eré náà ni "bàbá ìbejì"[2] Ó ti jẹ́ akópa, olùdarí àti olóòtú sinimá àgbéléwò rẹpẹtẹ bí i ìrèké oníbùdó àti 50-50, ní ọdún 1990 tí òṣèré apanilẹ́rìn-ín Bọ́lájí Amúṣan-án kópa nínú rẹ̀.[3][4]

Àwọn Ìtọ́kasíÀtúnṣe