Akin Adesokan je olukowe omo ile Naijiria[1]

Akin Adesokan
Iṣẹ́Onkòwé
Ọmọ orílẹ̀-èdèNàìjíríà

Igbèsi Àyè Àrakunrin naa

àtúnṣe

Akin Adesokan jẹ akọwè to lori àṣà ilẹ Afirica nibi toti jẹ associate professor ti comparative literature ni ilè iwè giga ti Indiana Bloomington[1][2][3].

Ni ọdun 1990, Akin lọsi ilè iwè giga ti ìlú Ibadan Adesokan gba MA ni ọdun 2003 ati Ph.D. lati ilè iwè giga ti Cornell ni ọdun 2005 nibi toti gba ẹbun gẹgẹbi akẹẹkọ to pegede julọ ninu department rẹ ni Theatre Arts. Arakunrin naa gba ẹbu ti Faculty ti Arts ati Apapọ Council ti Arts ati Àṣà.[4][5].

Ami Ẹyẹ

àtúnṣe

Akin Adesokan gba Ami Ẹyẹ ti PEN Freedom-to-Write ni ọdun 1998 ati Àmi Ẹyẹ ti Lillian Hellman-Dashuell Hammett Human Rights ni ọdun 1999[6].