Akinlade Abiodun Isiaq je ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà ati olóṣèlú to n ṣiṣẹ gẹgẹbi aṣoju ijọba àpapò ti o n ṣoju ẹkun Egbado South / Ipokia ti ìpínlè Ogun ni ile ìgbìmò aṣofin àgbà .[1] [2]

Awọn itọkasi

àtúnṣe