Akuoma Ugo Tracy Omeoga (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹfà ọdún 1992) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó tan mọ́ America, tó sì máa ń kópa nínú ìdíje Bobsleigh. Ó ṣojú orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nínú ìdíje eré-ìdárayá Bobsleigh, nínú Nigeria bobsled team, ní 2018 Winter Olympics.[1] Wọ́n bí Omegoa sí Saint Paul, Minnesota, àwọn òbí rẹ̀ sì koó kúrò ní Nàìjíríà, láti lọ sí ìlú America, láti lọ sí ilé-ìwẹ́. Ó lọ sí University of Minnesota, nígbà tó dàgbà.[2]

Akuoma Omeoga
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian, American
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kẹfà 1992 (1992-06-22) (ọmọ ọdún 32)
Saint Paul, Minnesota, United States
Sport
Erẹ́ìdárayáBobsleigh

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Empty citation (help) 
  2. Rosengren, John. "Speed Racer". minnesotaalumni.org. University of Minnesota. Retrieved June 28, 2020.