Aláàfin Olúàṣo
Aláàfin ìlú Ọ̀yọ́ nígbà kan rí
Aláàfin Olúàṣo jẹ́ ọba Ọ̀yọ́ tí ó gbajúgbajà fún ẹwà àti fìrìgbọ̀n rẹ̀. Àwọn àkọni ìgbà náà ṣàlàyè pé àsìkò tó jẹ Ọba Ọ̀yọ́, àlàáfíà, ẹ̀mí-gígùn àti ìfẹ́ jọba ní ìlú. Ó kọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àfin sí inú ìlú, ó sì fẹ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìyàwó, tí wọ́n sì bí ọmọ rẹpẹtẹ fún un.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Alaafin Oluaso: Wo Aláàfin tó bí ọmọ 1,460, ayaba mẹ́sàn-án bí ìbejì lọ́jọ́ kan ṣoṣo ní ìgbà mẹ́ta". BBC News Yorùbá. 2023-02-05. Retrieved 2024-06-20.
- Samuel Johnson, Obadiah Johnson. The History of the Yorubas, From the Earliest of Times to the Beginning of the British Protectorate. p 158