Al-Kahina
Al-Kahina (Lárúbáwá: الكاهنة), tí a mọ̀ sí Dihya, jẹ́ Berber Ọbabìnrin ti Aurès[2] àti adarí ẹ̀sìn àti àwọn ológun tí ó máa ń lé wájú àwọn aláàbò ọmọ ìlú sí Muslim conquest of the Maghreb, ẹ̀sìn tí wọ́n padà mọ̀ sí Numidia tí ó hàn pé wọ́n ń ṣẹ́gun àwọn ọmọ ogun Umayyad nínú Ogun tí Meskiana lẹ́yìn tí ó ti di adarí tí kò díje ti gbogbo ilẹ̀ Maghreb,[3][4][5][6] kí wọ́n tó fi ẹ̀tànjẹ ṣẹ́gun rẹ̀ ní Ogun Tabarka náà. Wọ́n bíi ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ 7th century AD ó sì kú ní lákòókò ìgbẹ̀yìn 7th century ní ayé òde-òní Algeria.
Al-Kahina | |
---|---|
Queen of the Aurès
| |
Dihya memorial in Khenchela, Algeria | |
Reign | Early seventh century |
Predecessor | Kusaila |
Father | Tabat[1] |
Died | 703 AD (in battle) Bir al-Kahina, Aurès[2] |
Àwọn Orírun àti ẹ̀sìn
àtúnṣeOrúkọ rẹ̀ alára jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn ọ̀wọ́ wọ̀nyí: Daya, Dehiya, Dihya, Dahya or Damya.[7] wọ́n mẹ́nubà ipò rẹ̀ nínú èdè Lárúbáwá tí ìpìlẹ̀ rẹ̀ jẹ́ al-Kāhina (the priestess soothsayer). Èyí ni orúkọ ìnagijẹ tí àwọn Mùsùlùmí olùbádíje rẹ̀ sọọ́ nítorí ẹ̀bun rírí ìṣẹ̀lẹ̀ ọjọ́-iwájú.[2] Wọ́n bíi sínú Jrāwa Zenata àwọn ẹ̀yà ìbẹ̀rẹ pẹ̀pẹ̀ 7th century.[8] Fún ọdún gbáko ni ó fi darí ìpínlẹ̀ Berber tí ó ní ìyánǹda láti Aurès Mountains náà lọ sí ilẹ̀ olómi nínú aginjù Gadames (ní 695–700 AD). Àmọ́ àwọn Arab, ṣàpọ́nlé nípa Musa bin Nusayr, pípadà pẹ̀lú àwọn ọmọ ogun tí wọ́n sánángun tí wọ́n sì ṣẹ́gun rẹ̀. Ó ja ogun tí El Djem orí-afárá gbọ̀ngán ìṣeré Róòmù àmọ́ tí wọ́n paá lẹ́yìn-ò-rẹyìn nínú ìkòdìmú lẹ́gbẹ kànǹga tí ó ṣì ń jẹ́ orúkọ rẹ̀, Bir al Kahina in Aures.[9]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedfather
- ↑ 2.0 2.1 2.2 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedEB1306
- ↑ The History of Anti-Semitism, Volume 2: From Mohammed to the Marranos Leon Poliakov University of Pennsylvania Press
- ↑ Remarkable Jewish Women: Rebels, Rabbis, and Other Women from Biblical Times to the Present Emily Taitz, Sondra Henry Jewish Publication Society,
- ↑ History of North Africa: Tunisia, Algeria, Morocco: From the Arab Conquest to 1830 Charles André Julien Praeger
- ↑ The Jews of North Africa: From Dido to De Gaulle Sarah Taieb-Carlen University Press of America,
- ↑ See discussion of these supposed names by Talbi (1971).
- ↑ Naylor, Phillip C. (2009) (in en). North Africa: A History from Antiquity to the Present. University of Texas Press. p. 65. ISBN 978-0292778788. https://books.google.com/books?id=a1jfzkJTAZgC.
- ↑ Charles André Julien; Roger Le Tourneau (1970). Histoire de L'Afrique du Nord. Praeger. p. 13. ISBN 9780710066145. https://books.google.com/books?id=tYZyAAAAMAAJ.