Alan Turing
Alan Mathison Turing, OBE, FRS ( /ˈtjʊərɪŋ/ TEWR-ing; 23 June 1912 – 7 June 1954), je ara Ilegeesi onimomathimatiki, onimo ogbon, aseatuwoipamo ati asesayensi komputa. O ko ipa pataki ninu idagbasoke sayensi komputa, nipa pipese isodimudaju awon itumo "algoritmu" ati "isiropo" ("computation") pelu ero Turin, to kopa pataki ninu idasile komputa odeoni.[1] Turing je gbigba bi baba sayensi komputa ati laakaye afowoda.[2]
Alan Turing | |
---|---|
Alan Turing | |
Ìbí | Maida Vale, London, England, United Kingdom | 23 Oṣù Kẹfà 1912
Aláìsí | 7 June 1954 Wilmslow, Cheshire, England, United Kingdom | (ọmọ ọdún 41)
Ibùgbé | United Kingdom |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | British |
Pápá | Mathematics, Cryptanalysis, Computer science |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Cambridge Government Code and Cypher School National Physical Laboratory University of Manchester |
Ibi ẹ̀kọ́ | King's College, Cambridge Princeton University |
Doctoral advisor | Alonzo Church |
Doctoral students | Robin Gandy |
Ó gbajúmọ̀ fún | Halting problem Turing machine Cryptanalysis of the Enigma Automatic Computing Engine Turing Award Turing Test Turing patterns |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Officer of the Order of the British Empire Fellow of the Royal Society |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedAFP
- ↑ Homer, Steven and Alan L. (2001). Computability and Complexity Theory. Springer via Google Books limited view. p. 35. ISBN 0-3879-5055-9. http://books.google.com/?id=r5kOgS1IB-8C&pg=PA35. Retrieved 2011-05-13.