{{subst:afd|help=off}}

Àdàkọ:Chembox KEGG
Alanine
{{{Alt}}}
{{{Alt}}}
Àwọn orúkọ mìíràn 2-Aminopropanoic acid
Identifiers
CAS number 338-69-2 (D-isomer)
PubChem 5950
ChEBI CHEBI:16977
SMILES
InChI
InChI key QNAYBMKLOCPYGJ-UHFFFAOYAA
ChemSpider ID 64234
Properties
Fọ́múlà mólékùlù C3H7NO2
Ìkójọ mọ́lù 89.09 g mol−1
Appearance white powder
Density 1.424 g/cm3
Ojúàmì ìyọ́

258 °C, 531 K, 496 °F

Solubility in water 167.2 g/L (25 °C)
Acidity (pKa) 2.35 (carboxyl), 9.69 (amino)[1]
 Àdàkọ:Cross(what is this?)  (verify)
Except where noted otherwise, data are given for materials in their standard state (at 25 °C, 100 kPa)
Infobox references

Alanine (gé kúrú sí Ala tàbí A;  ó ń kóòdù fún àwọn GCU, GCC, GCA, àti GCG) tí ó ń kóòdù fún GAA or GAG) jẹ́ α-amino tí wọ́n ń lò lati ṣèdá àwọn protein nínú ara. Ó ní α-amino lẹ́gbẹ́ kan (èyí tí ó ní agbára −NH3+ lábẹ́ ààyé), àti α-carboxylic acid lẹ́gbẹ́ kan (èyí tí kò ní agbára −COO− lábẹ́ ààyé), àti ẹgbẹ́ methyl tí ó somọ́ lẹ̀gbẹ́, tí a sì kó wọn pọ́ sí àwọn tí kò lágbára lati túká sómi, amino acid tí kò dẹ̀gbẹ́. Kò ṣe pàtàkì púpọ̀ lára àwọn ènìyàn, tí ó tùmọ sí wípé ara lè ṣẹ̀dá rẹ̀.

L-isomer rẹ̀ (apá òsì) ti alanine jẹ́ ìkan lára ogún  àwọn amino acid tí ó ń kóòdù fún àwọn kóòdù gene ara. L-Alanine jẹ́ ìkejì yàtọ̀ sí  leucine tí ó ṣẹlẹ̀ wípé  má a ń rí ní bí ìdá  7.8%  ní ìrísí rẹ̀ nínú àwọn tí àwọn nkan1,500 tí ó ní protein.[2] 

Ìṣẹ̀dá kẹ́míkà

àtúnṣe

A lè ṣẹ̀dá racemic alanine nípasẹ̀ yíyọ omi kúrò nínú acetaldehyde àti ammonium chloride lójú sodium cyanide nípasẹ̀ Strecker reaction, tàbí t ammonolysis  2-bromopropanoic acid:[3]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Dawson, R.M.C., et al., Data for Biochemical Research, Oxford, Clarendon Press, 1959.
  2. Doolittle, R. F. (1989), "Redundancies in protein sequences", in Fasman, G. D., Prediction of Protein Structures and the Principles of Protein Conformation, New York: Plenum, pp. 599–623, ISBN 0-306-43131-9 .
  3. Kendall, E. C.; McKenzie, B. F. (1929). "dl-Alanine".