Alasdair MacIntyre

Alasdair Chalmers MacIntyre (ojoibi 12 Osu Kinni 1929) je is a Scottish amoye ara Skotland to gbajumo pataki fun ipa re si imoye oniwarere ati oloselu sugbon to tun gbajumo fun ise re lori itan imoye ati oro-olorun. Ohun ni Elegbe Iwadi Agba ni Gbangan awon Eko Aristoteli ninu Iwuwa ati Iselu ni Yunifasity London Metripolitan ati Ojogbon Eye Imoye ni Yunifasity Notre Dame.

Alasdair Chalmers MacIntyre
(Photo Credit: Sean O'Connor)
OrúkọAlasdair Chalmers MacIntyre
Ìbí12 Oṣù Kínní 1929 (1929-01-12) (ọmọ ọdún 92)
Glasgow, Scotland
AgbègbèWestern Philosophy
Ẹ̀ka-ẹ̀kọ́Analytic Philosophy, Thomism
Ìjẹlógún ganganEthics, Metaethics, History of Ethics, Political Philosophy
Àròwá pàtàkìRevival of Virtue ethics, Internal and External Goods


ItokasiÀtúnṣe