Alberto Fujimori
Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Japan
- Láàrin orúkọ ará Japan yìí, orúkọ ìdílé ni Fujimori.
Orúkọ yìí lo àṣà ìṣorúkọ ní èdè Spéìn; àkọ́kọ́ tàbí orúkọ ìdílé bàbá ni Fujimori èkejì tàbí orúkọ ìdílé ìyà ni Fujimori.
Alberto Ken'ya Fujimori Fujimori (Pípè: [alˈβeɾto fuxiˈmoɾi] or [fuʝiˈmoɾi]; jp. 藤森アルベルト Fujimori Aruberuto; ojoibi 26 Oṣù Keje 1938 – o ku ni Oṣu Kẹsan Ọjọ 11, Ọdun 2024) je Aare ile Perú lati 1990 de 2000.
Alberto Fujimori | |
---|---|
Alberto Fujimori in Maryland, 3 Oṣù Kẹ̀wá 1998. | |
45th President of Peru | |
In office 28 Oṣù Keje 1990 – 22 Oṣù Kọkànlá 2000 | |
Asíwájú | Alan García |
Arọ́pò | Valentín Paniagua |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Lima, Peru | Oṣù Keje 26, 1938
Aláìsí | September 11, 2024 | (ọmọ ọdún 86)
Aráàlú | Peruvian, Japanese |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peru Change 90 (1990–1998) Yes Keep (1998-2010) Popular Force (2010-2024) Japan People's New Party (2007) |
Other political affiliations | Peru 2000 (1999-2005) Alliance for the Future (2005-2010) |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Susana Higuchi (1974-1994) Satomi Kataoka (2006-2024)[1] |
Àwọn ọmọ | Keiko Fujimori Hiro Alberto Sachi Marcela Kenji Fujimori |
Alma mater | La Molina National Agrarian University University of Wisconsin–Milwaukee |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ "Fujimori gets married from cell". BBC News. 6 April 2006. http://news.bbc.co.uk/2/hi/americas/4882550.stm.