Alemitu Bekele Aga ti a bini ọjọ kèji leelogun, óṣu August, ọdun 1976 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ ede Ethiopia to da lori ere sisa ti Idaji Marathon[1][2][3]..

Àṣèyọri àtúnṣe

Ni ọdun 1998, Aga kopa ninu idija agbaye ti Cross Country ni Marrakech, Morocco nibi to ti gbe ipo keji ninu idije ẹgbẹ. Ni ọdun 2008, Arabinrin naa jawe olubori ti Marathon Benelux[4].

Itọkasi àtúnṣe

  1. Marathon
  2. Alemitu BEKELE Profile
  3. Profile
  4. Benelux Marathon champion.