Alemitu Bekele Degfa
Alemitu Bekele Degfa ni a bini ọjọ kejila, óṣu september, ọdun 1977 jẹ elere sisa lobinrin ti órilẹ Ethiopia to da lori metres ti ẹgbẹrun marun[1].
Celebrating gold in Turin | |||||||||||||||||||||||||
Òrọ̀ ẹni | |||||||||||||||||||||||||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Turkish | ||||||||||||||||||||||||
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹ̀sán 1977 Shoa, Ethiopia | ||||||||||||||||||||||||
Ibùgbé | İstanbul, Turkey | ||||||||||||||||||||||||
Sport | |||||||||||||||||||||||||
Erẹ́ìdárayá | Running | ||||||||||||||||||||||||
Event(s) | 3000 metres, 5000 metres | ||||||||||||||||||||||||
Club | Üsküdar Belediyespor | ||||||||||||||||||||||||
Achievements and titles | |||||||||||||||||||||||||
Personal best(s) | 3000m: 8:35.19 5000m: 14:42.62 | ||||||||||||||||||||||||
Iye ẹ̀ṣọ́
|
Àṣèyọri
àtúnṣeBekele pari pẹlu ipo keje ninu ere olympic ti ọdun 2008. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa gba ami ẹyẹ ọla ti wura ninu idije ti inu ile ti ilẹ Ethiopia[2]. Ni ọdun 2010, Degfa kopa ninu idije ere sisa ti ilẹ Ethiopia ti ẹgbẹrun marun metres pẹlu iṣẹju 52.20 ati iṣẹju aya kẹrin lèèlogun. Ni ọdun 2010, Degfa kopa ninu Cup Continental ti IAAF to si gba ami ẹyẹ ọla ti silver[3]. Ni ọdun 2011, Degfa gba órukọ fun Üsküdar Belediyespor ni Cinque Mulini[4].