Alex Egbona (ojoibi October 15, 1964) je olóṣèlú ọmọ Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìjọba àpapọ̀ tó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Yakurr/Abi ní ìpínlẹ̀ Cross River . [1] O jẹ olùrànlọ́wọ́ pàtàkì, si Gómìnà ìpínlẹ̀ Cross River, lẹ́yìn náà ni wọ́n yàn án sípò ìgbákejì ọ̀gá àgbà àti ọmọ ìgbìmọ̀ aláṣẹ ìpínlẹ̀ Cross River.

Awọn itọkasi

àtúnṣe