Aleksandr Ankvab (Àdàkọ:Lang-ab, Rọ́síà: Александр Золотинскович Анкваб; ojoibi December 26, 1952) je oloselu ati onisowo ara Abkhaz to ti je Aare ile Abkhazia lati 2011. Labe Aare Sergei Bagapsh, o ti je Alakoso Agba tele lati 2005 de 2010 ati Igbakeji Aare lati 2010 de 2011.

Alexander Ankvab
Алеқсандр Анқәаб
President of Abkhazia
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
29 May 2011
Acting: 29 May 2011 – 26 September 2011
Alákóso ÀgbàSergei Shamba
Leonid Lakerbaia
Vice PresidentMikhail Logua
AsíwájúSergei Bagapsh
Prime Minister of Abkhazia
In office
14 February 2005 – 13 February 2010
ÀàrẹSergei Bagapsh
AsíwájúNodar Khashba
Arọ́pòSergei Shamba
Vice President of Abkhazia
In office
12 February 2010 – 29 May 2011
ÀàrẹSergei Bagapsh
AsíwájúRaul Khadjimba
Arọ́pòMikhail Logua
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí26 Oṣù Kejìlá 1952 (1952-12-26) (ọmọ ọdún 72)
Sukhumi, Soviet Union
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAitaira
Alma materRostov State University