Alexandre Dumas, bàbá

(Àtúnjúwe láti Alexandre Dumas, père)

Alexandre Dumas, bàbá, ibi Dumas Davy de la Pailleterie (24 July 1802 – 5 December 1870)[1] je olukowe omo orile-ede Fransi. Awon eniyan mo fun iwe to ko, ninu won ni The Count of Monte Cristo ati The Three Musketeers. Awon iwe re ti di ere to po ju 200, ton lo ni ore ede to ju 100. Iwe to ko gbeyin ni The Knight of Sainte-Hermine, shungban oku ki oto pari e,ni 2005 awon alakawe pari e fun.

Alexandre Dumas, père
Alexandre Dumas, père.
Iṣẹ́playwright and novelist
Ọmọ orílẹ̀-èdèFrench
Ìgbà1829–1870
Literary movementRomanticism and Historical fiction
Notable worksThe Count of Monte Cristo, The Three Musketeers

Signature


  1. Alexandre Dumas Archived 2009-10-31 at the Wayback Machine.on Encarta. 2009-10-31.