Alfred Adler
Alfred Adler jẹ́ oníṣègùn òyìnbó ọmọ orílẹ̀-èdè Austria. Wọ́n bí Adler ní ọdún 1870. Ó kú ní ọdún 1973 is. Ó jẹ́ oníṣègùn àrùn ọpọlọ tàbí wèrè (psychiatrist). Òun ni ó dá ilé-ẹ̀kọ́ tí ó n jé ‘School of Individual psychology’ sílẹ̀. Ọ̀gbẹ́ni Freud ni ó kókó n tè lé sùgbón ó yapa kúrò ní òdò rè lọ́dún 1911. Ó tako ìtẹmpẹlẹ mọ́ ọ̀rọ̀ ìbá ra-ẹnì lòpò (sex). Lójú rẹ̀, wàhálà tí ènìyàn ni láti sa agbára láti yọ ara eni kúrò ní ipò eni àá fojú ténbélú (inferiority Complex).
Alfred Adler | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Rudolfsheim, Austria | Oṣù Kejì 7, 1870
Aláìsí | May 28, 1937 Aberdeen, Scotland | (ọmọ ọdún 67)
Ibùgbé | Austria |
Orílẹ̀-èdè | Austrian |
Iṣẹ́ | Psychiatrist |
Gbajúmọ̀ fún | Individual Psychology |
Olólùfẹ́ | Raissa Epstein |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- Adler, A. (1908). Der Aggressionstrieb im Leben und der Neurose. Fortsch. Med. 26: 577-584.
- Adler, A. (1938). Social Interest: A Challenge to Mankind. J. Linton and R. Vaughan (Trans.). London: Faber and Faber Ltd.
- Adler, A. (1956). The Individual Psychology of Alfred Adler. H. L. Ansbacher and R. R. Ansbacher (Eds.). New York: Harper Torchbooks.
- Connell, R. W. (1995). Masculinities. Cambridge, UK: Polity Press.
- Dreikurs, R. & Soltz, V. (1964). Children the Challenge. New York: Hawthorn Books.
- Ehrenwald, J. (1991, 1976). The History of Psychotherapy: From healing magic to encounter. Northvale, NJ: Jason Aronson Inc.
- Eissler, K.R. (1971). Death Drive, Ambivalence, and Narcissism. Psychoanal. St. Child, 26: 25-78.
- Ellenberger, H. (1970). The Discovery of the Unconscious. New York: Basic Books.
- Fiebert, M. S. (1997). In and out of Freud's shadow: A chronology of Adler's relationship with Freud. Individual Psychology, 53(3), 241-269.
- Freud, S. (1909). Analysis of a Phobia in a Five-Year-Old Boy. Standard Edition of the Works of Sigmund Freud, London: Hogarth Press, Vol. 10, pp. 3–149.
- King, R. & Shelley, C. (2008). Community Feeling and Social Interest: Adlerian Parallels, Synergy, and Differences with the Field of Community Psychology. Journal of Community and Applied Social Psychology, 18, 96-107.
- Manaster, G. J., Painter, G., Deutsch, D., & Overholt, B. J. (Eds.). (1977). Alfred Adler: As We Remember Him. Chicago: North American Society of Adlerian Psychology.
- Shelley, C. (Ed.). (1998). Contemporary Perspectives on Psychotherapy and Homosexualities. London: Free Association Books.
- Slavik, S. & King, R. (2007). Adlerian therapeutic strategy. The Canadian Journal of Adlerian Psychology, 37(1), 3-16.
- Gantschacher, H. (ARBOS 2007). Witness and Victim of the Apocalypse, chapter 13 page 12 and chapter 14 page 6.
- Orgler, H. (1996). Alfred Adler, 22 (1), pg. 67-68.