Alhaji Yahaya Madawaki
Alhaji Yahaya Madawaki, MFR, OBE, DLL, oloye ti King George VI da lọ́lá ni ( Oṣù Kiini 1907 títí di ojo Karùn-ún Osu Kẹfà, 1998) jẹ́ gbajúmò Òṣèlú orile-ede Naijiria. O ,ti fi igbakan je Minisita fun Ètò ilera, Madawaki ti Ilorin ati Atunluse ti Erin-ile ni Ìpínlẹ̀ Kwara.[1][2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Ilorin: the journey so far. L. A. K. Jimoh. 1994. ISBN 9789783283503. https://books.google.com/books?id=pYouAQAAIAAJ&q=Alhaji+Yahaya+Madawaki+Nigerian+politician. Retrieved September 18, 2016.
- ↑ "Report ... for the period October 1, 1960, to December 31, 1965". Federal Ministry of Information, Printing Division. 1967. Retrieved September 18, 2016.