Ali Hassan al-Majid

Ali Hassan al-Majid ti won maa n pe ni Chemical Ali ti o je ara ile ti o je ara ile Sadam Hussein ni won ti dajo iku fun ipa ti o ko nitori ipolongo ti o se tako awon Kurds ni 1988.