Alice Ann Munro (oruko baba Laidlaw; ojoibi 10 July 1931) je olukowe ara Kanada to unkowe ni ede Geesi. O gba Ebun Nobel ninu Litireso fun odun 2013 ati Man Booker International Prize 2009 fun gbogbo ise owo re, bakanna o gba Governor General's Award Kanada ni emeta fun iwe itan akodun re.[2][3][4]

Alice Munro
Ọjọ́ ìbíAlice Ann Laidlaw
10 Oṣù Keje 1931 (1931-07-10) (ọmọ ọdún 89)
Wingham, Ontario, Canada
ÈdèEnglish
Ọmọ orílẹ̀-èdèCanadian
GenreShort stories
Notable awardsGovernor General's Award (1968, 1978, 1986)
Giller Prize (1998, 2004)
Man Booker International Prize (2009)
Nobel Prize in Literature (2013)
SpouseJames Munro (1951–1972)
Gerald Fremlin (1976–2013)ItokasiÀtúnṣe