Aliko Dangote

Gbajumo Onisowo

Aliko Dangote Ha-Aliko Dangote.ogg listen GCON (ojoibi 10 April 1957) jẹ́ onísòwò àti ọlọ́rẹ ará Nàìjíríà tí ó olùdásílẹ̀ àti alága ilé-isẹ́ Dangote Group, ilé-isẹ́ aloẹ̀rọ gbàǹgbà ní Áfríkà.[2]

Alhaji
Aliko Dangote
MFR, GCON
Dangote at the World Economic Forum, 2011
Ọjọ́ìbíAliko Dangote
10 Oṣù Kẹrin 1957 (1957-04-10) (ọmọ ọdún 67)
Kano, Northern Nigeria,
British Nigeria
(now Kano, Nigeria)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Government College, Birnin Kudu
Iléẹ̀kọ́ gígaAl-Azhar University, Cairo
Iṣẹ́Industrialist and philantrophist
Ìgbà iṣẹ́1977—present
Gbajúmọ̀ fúnFounding and leading the Dangote Group
Net worthUS$7.7 billion (April 2020)[1]
Àwọn ọmọ3 daughters including Halima Dangote;

Gbogbo ohun ìní rẹ̀ ẹ́ tó US$8.1 billion (March 2020)[1], ní January 2020, òhun ni ẹni ọlọ́lájùlọ 88k ni agbaye àti ẹni ọlọ́rọ̀ jùlọ ní ilẹ̀ Áfríkà.[3]

Ní Oṣù kọkànlá ọdún 2021, Sani Dangote, Igbákejì Alákoso (VP) ti Ẹgbẹ́ Dangote àti àbúro Aliko Dangote, kú.



  1. 1.0 1.1 "Aliko Dangote". Forbes. Retrieved 16 October 2019. 
  2. "History & Strategy – Dangote Industries Limited" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-03-15. 
  3. Nsehe, Mfonobong (5 March 2013). "The Black Billionaires 2013". Forbes. Retrieved 3 May 2015.