Aliyu Mohammed Gusau
Olóṣèlú
Aliyu Mohammed Gusau (ojoibi May 18 1943) oga agbogun ara Naijiria to ti feyinti. O ti je Alakoso Oro Abo, Onimoran Oro Abo Orile-ede fun aare Naijiria otooto meji, Oga awon Omose Agbogun, o se olori fun orisirisi ile-ise otelemuye, besini o tun se Oga Alase Nigerian Defence Academy.[1]
Aliyu Mohammed Gusau | |
---|---|
Minister of Defence | |
In office 5 March 2014 – May 2015 | |
Asíwájú | Olusola Obada |
Arọ́pò | Mansur Dan Ali |
Chief of Army Staff | |
In office August 1993 – September 1993 | |
Asíwájú | Salihu Ibrahim |
Arọ́pò | Chris Alli |
National Security Advisor | |
In office 29 May 1999 – 1 June 2006 | |
Arọ́pò | Abdullahi Sarki Mukhtar |
National Security Advisor | |
In office 8 March 2010 – September 2010 | |
Asíwájú | Abdullahi Sarki Mukhtar |
Arọ́pò | Kayode Are |
Director General of the National Security Organization | |
In office September 1985 – July 1986 | |
Asíwájú | Mohammed Lawal Rafindadi |
Arọ́pò | NSO Dissolved |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 18 Oṣù Kàrún 1943 Gusau, Zamfara State, Nigeria |
Alma mater | Nigerian Defence Academy |
Military service | |
Branch/service | Nigerian Army |
Years of service | 1964 - 1993 |
Rank | Lieutenant General |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Ibrahim Auduson (9 March 2010). "The Return of General Aliyu Gusau". Daily trust. Retrieved 21 April 2010.