Allwell Adémọ́lá tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Ọjọ́ Kẹ̀sán-án oṣù kẹjọ ọdún 1983 jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèrébìnrin, olùdarí, oǹkọ̀tàn, akọrin àti olóòtú sinimá àgbéléwò ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọmọ-ọmọbìnrin adájọ́-àgbà jùlọ àkọ́kọ́ ní Nàìjíríà, Adájọ́-Àgbà, Olóògbé Adétòkunbọ̀ Adémọ́lá . [1]

Ìkẹ́kọ̀ọ́ àti ìgbà èwe rẹ̀

àtúnṣe

Ó kàwé gbàwé ẹ̀rí ní ifáfitì ìjọba àpapọ̀ tó gúnwà sí Ilé-Ifẹ̀, OAU. Allwell bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò láti èwe ṣùgbọ́n ní ọdún 2008 ni ó bẹ̀rẹ̀ sí ní gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré sinimá àgbéléwò. Láti ìgbà náà, ó ti kópa nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ sinimá àgbéléwò, lára àwọn sinimá-àgbéléwò tó gbé ìràwọ̀ rẹ̀ síta ni; Láródó Ọjọ́, Etí kẹta, Ọmọ Ẹ̀mí, You. Or I, Ayé Kejì.[2]

Àtòjọ díè nínú àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Allwell Ademola Biography: Age, Movies". 360dopes. 2018-07-29. Retrieved 2020-02-09. 
  2. [/allwell-ademola-biography-profile-fabwoman/ "Allwell Ademola Biography - Profile"] Check |url= value (help). FabWoman | News, Style, Living Content For The Nigerian Woman. 2019-08-09. Retrieved 2020-02-09.