Aloÿs Nizigama
Aloÿs Nizigama (ti a bi ni ọjọ kejidinlogun osu Okudu ọdun 1966) jẹ asare olona jinjin ọmọ ilu orilẹ-ede Burundi ti o ti fẹhinti ti o iṣe re je ti mita 5000 ati 10,000 .
Ninu iṣẹ rẹ, Nizigama sa ere-ije ni iṣẹju 21 ati iṣẹju-aaya-28 ni 10,000 Mita , ni ipo keji si Haile Gebrselassie pẹlu akoko 23. [1]
Ìdíje Okeere
àtúnṣe1991 | World Championships | Tokyo, Japan | 6th | 10,000 m |
1993 | World Championships | Stuttgart, Germany | 7th | 5,000 m |
5th | 10,000 m | |||
1996 | Olympic Games | Atlanta, United States | 4th | 10,000 m |
2000 | Olympic Games | Sydney, Australia | 9th | 10,000 m |
2001 | Jeux de la Francophonie | Ottawa-Hull, Canada | 3rd | 10,000 m |