Amilcar Cabral
(Àtúnjúwe láti Amílcar Cabral)
Amílcar Lopes da Costa Cabral (Pípè ni Potogí: [ɐˈmilkaɾ ˈlɔpɨʃ kɐˈbɾal]; 12 Oṣù Kẹ̀sán 1924 – 20 Oṣù Kínní 1973) jẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ iṣẹ́-àgbẹ̀, olùkọwé, Marksistì, agbógunti ìmúnisìn àti olóṣèlú ará Guinea-Bissau.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |