Amal Ayouch (tí a bí ní ọdún 1966) jẹ́ òṣèré ìlú Morocco, àti ọdún 1990 ni ó tín ṣe eré, lórí ìtàgé àti nínú fíìmù pẹ̀lú Èdè Faransé. [1] Ní oṣù kìíní ọdún 2015, wọ́n fún ni àmì ẹ̀yẹ àpónlé ní àyàjò àwọn obìnrin òṣèré tí ó wà yẹ ní Brazzaville [2][3] Ayouch ti kópa iwájú nínú Morocco's Fondation des arts vivants (Ìpìlẹ̀ àwọn àwòrán tí ó ń gbé)[4]

Àwọn Eré Rẹ̀ àtúnṣe

Sinimá àtúnṣe

Ọdún Fíìmù Olùdarí Ipa Àkíyèsí
2017 Palestina Julio Soto ati Mohamed El Badaoui Ismahan Eré SPanish
Little Horror Movie Jérôme Cohen Olivar Mrs Mancherbreuk
2016 Riad de mes rêves Zineb Tamourt Fíìmù kúkurú
2015 Les larmes de Satan Hicham Jebbari Meriem
Jérôme Cohen Olivar Soraya
2014 Sotto Voce Kamal Kamal Fatma
2013 L'Anniversaire Latif Lahlou Ghita
2012 Derriere-les-portes-fermees Ahd Bensouda Najia l’avocate
Le Retour du fils Ahmed Boulane elle-même fíìmù kúkurú
2011 Rihanna Mourad El Khaoudi fíìmù kúkurú
2010 Les ailes de l'amour Abdelhay Laraki Hajja Hlima
Femmes en miroirs Saad Chraibi tante Ghita
2009 Entropya Yassine Marroccu fíìmù kúkurú
2008 La Française Souad El Bouhati Mme Laktani
Kandisha Jérôme Cohen Olivar Dr Maliki
2007 Les Anges de Satan Ahmed Boulane l’avocate
2006 Une gazelle dans le vent Mohamed Hassini
Le jeu de l'amour Driss Chouika
2005 La danse du foetus Mohamed Mouftakir fíìmù kúkurú
2004 L'ascenseur Selma Bargach fíìmù kúkurú
Good bye Khadija Kamal Belghmi fíìmù kúkurú
Tabite or not Tabite Nabyl Lahlou Farida Fatmi
La mer Rachida Saadi fíìmù kúkurú
Sang d'encre Layla Triqui fíìmù kúkurú
2002 Casablanca Casablanca Farida Belyazid Amina
2001 Les années de l'exil Nabyl Lahlou Tamerdokht
2000 Ali Zaoua Nabil Ayouch Ali Zaoua's mother
Les lèvres du silence Hassan Benjelloun Aicha l’institutrice
1999 Histoire d'une rose Majid Rchich
1998 Destin de femme Hakim Noury Saida
1997 Les amis d'hier Hassan Benjelloun l'étudiante

Awọn itọkasi àtúnṣe

  1. "Amal Ayouch". AlloCine. Retrieved 13 October 2018. 
  2. Bouhrara, Imane (15 March 2007). "Amal Ayouch, l'artiste philosophe" (in French). Maghress. Retrieved 13 October 2018. 
  3. "Amal Ayouch primée au Festival du film des femmes africaines de Brazzaville" (in French). AtlasInfo. 15 January 2015. Retrieved 13 October 2018. 
  4. Jadraoui, Siham. "Fondation des arts vivants : du théâtre pour les quartiers défavorisés" (in French). Aujourd'hui. Retrieved 13 January 2010.