Amanda Ebeye

Òṣéré orí ìtàgé

Amanda Mike-Ebeye (tí a bí ní 30 Oṣù Kẹẹ̀rin ọdún 1986) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti afẹwàṣiṣẹ́. Ó gbajúmọ̀ fún àwọn ipa rẹ̀ nínu eré Clinic Matters[1] àti Super Story.

Amanda Mike-Ebeye
Ọjọ́ìbí30 Oṣù Kẹrin 1986 (1986-04-30) (ọmọ ọdún 38)
Nigeria
Iṣẹ́Oṣere, Afẹwaṣiṣẹ
Ìgbà iṣẹ́2008–iwoyi

Iṣẹ́ ìṣe

àtúnṣe

Ó ṣe ìṣàfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ nínu fíìmù níbi eré Weeping Tiger (2008).[2]

Nínu ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwò kan ti 2013 èyí tí Information Nigeria ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀, Ebeye fi hàn pé òun le ṣe eré oníhòhò fún owó tí ó tó ọ̀kẹ́ dọ́là lọ́nà àádọ́ta.[3]

Ìgbé ayé rẹ̀

àtúnṣe

Ebeye jẹ́ ẹ̀yà Agbor ti Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà. Ó jẹ́ àkẹ́ẹ̀kọ́-gboyè ní ilé-ìwé gíga Benson Idahosa nínu ìmọ̀ òṣèlú Káríayè.[4] Ní ọdún 2016, ó bí ọmọkùnrin kan ní Ìlú Kánádà.[5]

Ìwé ìròyìn kan (The Authority) fí hàn pé Ebeye sọ nínu ìfìwéránṣẹ́ Instagram rẹ̀ kan wípé òun kò lérò pé òún ní ìrètí láti bímọ níbẹ̀rẹ̀, ṣùgbọ́n láti ìgbà tí òún ti bí ọmọkùnrin rẹ̀ òún dúpẹ́ fún Ọlọ́run tó fi ọmọ náà taá lórẹ.[6] Ní ọdún 2016, ìyá Ebeye ṣe ìgbeyàwó lẹ́ẹ̀kan si.[7]

Àkójọ àwọn eré rẹ̀

àtúnṣe
  • The Pastor's Daughter
  • Desire
  • My Last Wedding
  • 100% Secret (2012)[8]
  • Weeping Tiger
  • Within Tiger
  • Keep my Love
  • Super Story (More than a friend, 2008)
  • Super Story (Blast from past, 2007)
  • It's Her Day [9]
  • Tales of Women[10]
  • The Evil Seed[11]
  • Agwonma: The Unbreakable Egg[12]
  • Sorrowful Heart[13] (pẹ̀lú Ebube Nwagbo àti Yul Edochie)
  • Everyday People (TV series)[14]
  • Indecent Lover (Film)[15]


Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Having a child is my best decision – Amanda Ebeye". Punch Newspapers. http://punchng.com/having-a-child-is-my-best-decision-amanda-ebeye. 
  2. "My career, parts of my body I love — Amanda Ebeye, actress". ModernGhana.com. Retrieved 3 August 2017. 
  3. "For $50 Million, I Can Act Unclothed – Actress Amanda Ebeye Reveals". Information Nigeria. Retrieved 3 August 2017. 
  4. "Men! I hate to see them around me â€" Amanda Ebeye". Vanguardngr.com. 19 June 2009. Retrieved 8 August 2017. 
  5. "Nollywood actress, Amanda Ebeye is now a mum!". 
  6. "I didn't really want kids' - Actress Amanda Ebeye". Authority Newspaper. Archived from the original on 2017-06-06. Retrieved 2017-08-03.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Nollywood actress, Amanda Ebeye's mum remarries". Archived from the original on 3 August 2017. Retrieved 17 August 2017.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "Amanda Ebeye - Nollywood Forever Movie Reviews". Nollywoodforever.com. Archived from the original on 3 August 2017. Retrieved 3 August 2017. 
  9. "Nigeria: Bovi's It's Her Day Premieres Today". allAfrica.com. Retrieved 2017-08-03. 
  10. Bada, Gbenga. ""Tales Of Women": Watch Taiwo Oduala"s new movie trailer". pulse.ng. Archived from the original on 3 August 2017. Retrieved 3 August 2017. 
  11. Mindspace, Nollywood (24 March 2014). "Nollywood by Mindspace: AMANDA EBEYE STARS IN 'THE EVIL SEED'". blogspot.com.ng. Retrieved 3 August 2017. 
  12. Izuzu, Chidumga. "Agwonma: Francis Duru, Amanda Ebeye, Ejike Asiegbu, others star in new movie". pulse.ng. Archived from the original on 3 August 2017. Retrieved 3 August 2017. 
  13. "NOLLYWOOD YUL EDOCHIE, EBUBE NWAGBO, AND AMANDA EBEYE, STAR IN ‘SORROWFUL HEART’". dailymedia.com.ng. Archived from the original on 20 October 2017. Retrieved 3 August 2017. 
  14. Izuzu, Chidumga. "#ThrowbackThursday: Do you remember hit TV series "Everyday People?"". Pulse.ng. Archived from the original on 3 August 2017. Retrieved 19 August 2017. 
  15. irokotv | NOLLYWOOD (2016-08-31), Indecent Lover - Latest 2016 Nigerian Nollywood Drama Movie [English], retrieved 17 August 2017