Amara Chyna Iwuanyanwu jẹ́ olóṣèlú Nàìjíríà. O jẹ igbákejì olori ile ìgbìmò aṣofin ipinlẹ Imo, to n ṣoju ẹkun ìdìbò ìpínlè Nwangele. [1] [2]