Amina Bilali
Amina Ally Bilali jẹ́ ogbóǹtarìgì agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ède Tanzania tí ó ṣeré ipò àárínlórí pápá fún Yanga Princess àti ẹgbẹ́ <a href="./Boolu-afesegba" rel="mw:WikiLink" data-linkid="5" data-cx="{"adapted":true,"sourceTitle":{"title":"Association football","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/a/ad/Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg/80px-Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg","width":80,"height":54},"description":"Team[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] sport played with a spherical ball","pageprops":{"wikibase_item":"Q2736"},"pagelanguage":"en"},"targetTitle":{"title":"Boolu-afesegba","thumbnail":{"source":"https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/a/ad/Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg/80px-Football_in_Bloomington%2C_Indiana%2C_1996.jpg","width":80,"height":54},"pageprops":{"wikibase_item":"Q2736"},"pagelanguage":"yo"},"targetFrom":"link"}[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]" class="cx-link" id="mwCQ" title="Boolu-afesegba">agbábọ́ọ̀lù</a> àwọn obìnrin Tanzania .
Isẹ́ òkè-òkun
àtúnṣeAlly di olórí ẹgbẹ agbábọ́ọ̀lù àwọn obìnrin Tanzania ní ìdíje COSAFA Women’s Championship ti ọdún 2020 àti ìdíje COSAFA Women’s Championship ti ọdún 2021 .
Wọ́n fún ní ipò akọni ìparí ìdíje tako Malawi èyítí wọ́n àwọ̀n kan si òdo (1–0) tí ó wáyé nípasẹ̀ Enekia Kasonga tí ó sì jẹ́ òṣèré ìdíje náà.
Àwọn ọlá
àtúnṣe- CECAFA Women ká asiwaju : 2018
- Asiwaju Awọn Obirin COSAFA : 2021
- Oṣere asiwaju Awọn Obirin COSAFA ti idije naa: 2021