Amina Oyiza Bello
Amina Oyiza Bello, tí wọ́n bí lọ́jọ́ kejì oṣù kẹrin ọdún (2 April 1978) jẹ́ agbẹjọ́rò, afowóṣàánú àti ìyàwó Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kogi, Yahaya Bello, Kogi State Governor. Òun ni Alága àti olùdásílẹ̀ Fairplus International, Hayat Foundation, bẹ́ẹ̀ náà lọ jẹ́ pàràkòyí oníṣòwò. [1][2]
Amina Oyiza Bello | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 2 Oṣù Kẹrin 1978 Kuroko, Ìpínlẹ̀ Kogi |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | University of Leicester Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀ University |
Olólùfẹ́ | Yahaya Bello |
Amina kàwé gboyè nínú ìmọ̀ òfin láti Obafemi Awolowo University ní Ilé-ìfẹ́ ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní Nàìjíríà.[3]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "My Hayat story". Archived from the original on 2017-11-13. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ ""I was advised to inject my son with a lethal substance to end the shame" – Kogi First Lady, Amina Oyiza Bello Speaks on Cerebral Palsy" (in en-US). Motherhood In-Style Magazine. 2017-02-10. http://motherhoodinstyle.net/2017/02/10/i-was-advised-to-inject-my-son-with-a-lethal-substance-to-end-the-shame-kogi-first-lady-amina-oyiza-bello-speaks-on-cerebral-palsy/.
- ↑ "Barrister Amina Oyiza Yahaya Bello : Passionately making a difference" (in en-US). Chiomah's Blog. 2017-03-16. http://www.chiomah.net/2017/03/barrister-amina-oyiza-yahaya-bello-passionately-making-a-difference.html?189db0.