Rómù Ayéijọ́un

(Àtúnjúwe láti Ancient Rome)

Rómù Ayéijọ́un jẹ́ àṣàọlàjú ti abúlé adákọ kékeré kan ní ẹ̀bá Peninsula Italia lati igba orundun 10k SK. O budo si eti Omiokun Mediteranean, ni ilu Romu, o di ikan larin awon ileobaluaye titobijulo ni agbaye ayeijoun.[1]

Àwọn ìtókasí

àtúnṣe
  1. Chris Scarre, The Penguin Historical Atlas of Ancient Rome (London: Penguin Books, 1995).