Andrés Iniesta
Andrés Iniesta Luján (tí a bí ní ọjọ́ kọkànlá Oṣù karùn-ún ọdún 1984) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè Spain. Ó wà lára àwọn tí ọ̀pọ̀ kà sí agbábọ́ọ̀lù àárín tí ó da jù ní àgbáyé.[3][4][5] Iniesta lọ ọ̀pọ̀lopọ̀ ọdún rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi agbábọ́ọ̀lù ní Barcelona, ní ibi tí ó ti jẹ́ adarí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù náà fún ṣáà mẹ́ta.
Iniesta with Spain in 2017 | |||
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 11 Oṣù Kàrún 1984[1] | ||
Ibi ọjọ́ibí | Fuentealbilla, Spain | ||
Ìga | 1.71 m[2] | ||
Playing position | Midfielder | ||
Number | 8 | ||
Youth career | |||
1994–1996 | Albacete | ||
1996–2001 | Barcelona | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2000–2003 | Barcelona B | 49 | (5) |
2002–2018 | Barcelona | 442 | (35) |
2018–2023 | Vissel Kobe | 114 | (21) |
National team | |||
2000 | Spain U15 | 2 | (0) |
2000–2001 | Spain U16 | 7 | (1) |
2001 | Spain U17 | 4 | (0) |
2001–2002 | Spain U19 | 7 | (1) |
2003 | Spain U20 | 7 | (3) |
2003–2006 | Spain U21 | 18 | (6) |
2006–2018 | Spain | 133 | (15) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 19:47, 1 July 2023 (UTC). † Appearances (Goals). |
Iniesta ran orílẹ̀ èdè Spain lọ́wọ́ láti jáwé olúborí nínú UEFA Euro 2008. Iniesta tún agbábọ́ọ̀lù gbòógì tí ó ran ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Spain láti jáwé olúborí nínú 2010 FIFA World Cup.
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedfifadata
- ↑ "Andrés Iniesta". FC Barcelona. Archived from the original on 28 November 2017. Retrieved 21 April 2018.
- ↑ "The 10 Greatest Midfielders In Football History Have Been Named And Ranked". www.sportbible.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 25 March 2021. Archived from the original on 16 June 2021. Retrieved 15 June 2021.
- ↑ HS, Shreyas (12 February 2021). "10 greatest midfielders of all time". www.sportskeeda.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 10 July 2021.
- ↑ Rogers, Joshua (21 May 2018). "Vote on where Iniesta ranks among the greatest midfielders of all time". mirror (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 15 June 2021.