Andrés de Santa Cruz

Olóṣèlú Ọmọ Orílẹ̀-èdè Spain

Andrés de Santa Cruz je Aare ile Bòlífíà elekeje ni odun 1827. Ojo ibi ni ojo karun, osu kejila, odun 1792 (5th Dec, 1792) ni Huarina, Bolifia. O si ipo padap ni ojo keedogbon, osu kesan, odun 1865 (25th September, 1865) ni Beauviour, Manche France. E ni ti o je are Bolifia leyin re ni Manuel Salanzar y Banquijano. Awon obi re ni Jose de Santa Cruz y Villavcen ati arabirin Juana Basilla Calahumana.ItokasiÀtúnṣe