Andrea Pirlo
Andrea Pirlo (tí a bí ní ọjọ́ kọkàndínlógún 1979) jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀ èdè Italy tí ó jẹ́ olùtoni àgbà ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Serie B Sampdoria.[3] Ó wà lára àwọn tí ọ̀pọ̀lopọ̀ kà sí agbábọ́ọ̀lù ipò àárín tí ó da jùlọ.[4][5][6]
Pirlo ní Juventus ní 2014 | |||
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 19 Oṣù Kàrún 1979[1] | ||
Ibi ọjọ́ibí | Flero, Italy[2] | ||
Ìga | 1.77 m[2] | ||
Playing position | Midfielder | ||
Youth career | |||
1992–1995 | Brescia | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
1995–1998 | Brescia | 47 | (6) |
1998–2001 | Inter Milan | 22 | (0) |
1999–2000 | → Reggina (loan) | 28 | (6) |
2001 | → Brescia (loan) | 10 | (0) |
2001–2011 | AC Milan | 284 | (32) |
2011–2015 | Juventus | 119 | (16) |
2015–2017 | New York City FC | 60 | (1) |
Total | 570 | (61) | |
National team | |||
1994 | Italy U15 | 3 | (0) |
1995 | Italy U16 | 6 | (2) |
1995 | Italy U17 | 4 | (0) |
1995–1997 | Italy U18 | 18 | (7) |
1998–2002 | Italy U21 | 40 | (16) |
2004 | Italy Olympic (O.P.) | 6 | (0) |
2002–2015 | Italy | 116 | (13) |
Teams managed | |||
2020 | Juventus U23 | ||
2020–2021 | Juventus | ||
2022–2023 | Fatih Karagümrük | ||
2023– | Sampdoria | ||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Pirlo bẹ̀rẹ̀ sí ń gba bọ́ọ̀lù fún ẹgbẹ́ Brescia ní ọdún 1995, ó jáwé olúborí borí Serie B ní ọdún 1997. Ó fọwọ́ síwẹ̀ fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Serie A ti Inter Milan lẹ́yìn ọdún kan, ṣùgbọ́n ó padà lọ sí ẹgbẹ́ AC Milan ní ọdún 2001. Ní ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù náà ní Pirlo ti di ògbóòntarìgì agbábọ́ọ̀lù, ó jáwé olúborí nínú ipò Serie A méjì, UEFA Champions League méjì, UEFA Super Cup méjì, FIFA Club World Cup méjì, Coppa Italia méjì, àti Supercoppa Italiana kan.[6]
Àwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedItaly - A. Pirlo - Profile - Soccerway
- ↑ 2.0 2.1 "Andrea Pirlo". Juventus F.C. Archived from the original on 24 April 2012.
- ↑ Andrea Pirlo named manager of Serie B side Sampdoria https://www.sportinglife.com/football/news/andrea-pirlo-named-manager-of-serie-b-side-sampdoria/210346
- ↑ "Born Again: How the Deep-Lying Midfielder Position is Reviving Careers". Soccerlens. 31 July 2009. Retrieved 15 May 2012.
- ↑ "Andrea Pirlo: Player Profile". ESPN FC. Retrieved 4 September 2013.
- ↑ 6.0 6.1 "A.C. Milan Hall of Fame: Andrea Pirlo". A.C. Milan. Retrieved 31 March 2015.