Andrew Fielding jẹ́ ọmọ bíbí ìlú Hampstead, ní ìlú London ní orílẹ̀-èdè England. A bi nínú oṣù Belu, ó si kú ní ọgbọ̀n ọjọ́ oṣù Èbìbì ọdún 2012. Ó jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ ìwádí Òun pẹ̀lú Alan àti john Carew lórí ìmọ̀ oògùn. Ìwádí rẹ̀ dálé ìmọ̀ Iṣan ara àti pataki lori ìbáṣepọ̀ iṣan nínú ara. Ó jẹ́ Ààrẹ fún àwọn Royal society láti ọdún 1980 sí 1985.[1]

Awon itokasi

àtúnṣe
  1. "Sir Andrew Fielding Huxley". Encyclopedia Britannica. 1917-11-22. Retrieved 2020-03-03.