Anglican Diocese ti Akoko Edo
Anglican Diocese ti Akoko Edo[1] jẹ́ ọ̀kan nínú mẹ́sàn án láàrín àwọn ẹ̀ka ìjọ Anglican tí ó wà ní Bendel[2]. Bíṣọ́ọ́bù tó ń darí lọ́wọ́ níbẹ̀ ni Jolly Ehigiator Oyekpen.
Note
àtúnṣe- ↑ "Anglican Communion: Diocese". Anglican Communion Website. Retrieved 2022-02-13.
- ↑ Adighibe, Ngozi (2020-03-22). "Our Provinces". Church of Nigeria (Anglican Communion). Retrieved 2022-02-13.