Anita Amenuku
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù Keje ọdún 1985 | ||
Playing position | Iwájú | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Ghatel Ladies | |||
National team‡ | |||
Ghana | 2 | (0) | |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Anita Amenuku tí a bí ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù Keje ọdún 1985 jẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá obìnrin ará ilẹ̀ Ghana kan tí mú ipò iwájú lórí pápá . Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá àwọn obìnrin ti orílẹ̀-ède Ghana. Ó wà lára àwọn tí ó kópa níbi FIFA Women's World Cup ti ọdún 2007 . Lórí ìpele ẹgbẹ́, ó ṣeré fún Ghatel Ladies ní Ghana. [1] Ó kọ́kọ́ fara hàn lórí pápá fún Ghana lòdì sí Australia ní ọjọ́ kejìlá Oṣù Kẹẹ̀sán ọdún 2007 . [2]
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣeÀdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World CupÀdàkọ:Ghana squad 2007 FIFA Women's World Cup