Ann Aluoch
Ann Aluoch Jẹ agbabọọlu lobinrin órilẹ ede kẹnya ti a bini 5, óṣu january ni ọdun 1990. Agbabọọlu naa ṣere gẹgẹbi defender[1][2][3].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Ann Aluoch Onyango | ||
Ibi ọjọ́ibí | Nairobi, Kenya | ||
Playing position | Defender | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
Spedag | |||
National team | |||
Kenya women's national football team | |||
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only. † Appearances (Goals). |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Ann kopa ninu Nations Cup awọn obinrin ilẹ afirica to waye ni ọdun 2016[4].