Ann Mukoro
Ann Mukoro jẹ Obinrin agbàbọọlu orilẹ ede Naigiria ti a bini 27, óṣu May ni ọdun 1975. Elere naa ṣere fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu gẹgẹbu Midfielder[1].
Personal information | |||
---|---|---|---|
Ọjọ́ ìbí | 27 Oṣù Kàrún 1975 | ||
Playing position | Midfielder | ||
National team‡ | |||
Nigeria women's national football team | |||
† Appearances (Goals). ‡ National team caps and goals correct as of 5 June 1995 (before the 1995 FIFA Women's World Cup) |
Àṣeyọri
àtúnṣe- Ni ọdun 1991 ati 1995, Arabinrin na kopa ninu ere idije Cup FIFA awọn obinrin agbaye[2].