Anneri Ebersohn

Ìròyìn ara ẹni

Ọjọ́ ìbí ọjọ́ kẹẹ̀sán Oṣù Kẹjọ ọdún 1990 (ọmọ ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n)

Ẹ̀kọ́ University of Pretoria

Gíga 1.68 m (5 ft 6 in)

Ìwọ̀n 57 kg (126 lb)

Eré ìdárayá

Eré ìdárayá Track and field

Event(s) 400 metres hurdles

Anneri Ebersohn tí a bí ní ọjọ́ kẹẹ̀sán Oṣù Kẹjọ ọdún 1990 jẹ́ olùsáré ìdárayá ti orílẹ̀ ède South Africa kan tí ó dojúkọ eré sísá oní fífò ti ọgọ́rún mẹ́rinmítà . [1] Ó ṣe aṣojú orílẹ̀-èdè rẹ̀ níbi World2013 Championship ti ọdún 2013 ní Ilu Moscow, ó kùnà láti dé gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ ìparí.

Ipa rẹ̀ tí ó dára jùlọ jẹ 55.87, tí a ṣètò ní Potchefstroom ní ọdún 2013.

Ìdíje tí a kọ sílẹ̀

àtúnṣe
Representing   Gúúsù Áfríkà
2007 World Youth Championships Ostrava, Czech Republic 9th (h) 400 m hurdles 60.79
2012 African Championships Porto Novo, Benin 15th (h) 400 m hurdles 60.12
2013 Universiade Kazan, Russia 5th 400 m hurdles 57.58
3rd 4 × 400 m relay 3:36.05
World Championships Moscow, Russia 25th (h) 400 m hurdles 57.90
2014 African Championships Marrakech, Morocco 5th 400 m hurdles 56.71
2015 Universiade Gwangju, South Korea 9th (h) 400 m hurdles 57.91
6th 4 × 400 m relay 3:46.73
African Games Brazzaville, Republic of the Congo 4th 400 m hurdles 58.68

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. IAAF profile for Anneri Ebersohn